Example items (sample of 50)

sen_strnsubj_formnsubj_featurestreebank_link
Ọkùnrin yìí ń gbé nínú ìbojì , kò sí ẹni tí ó lè dè é mọ́ , kódà ẹ̀wọ̀n kò le dè é .ọkùnrin
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Wikipedia Yorùbá únlo àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ tó wà fún Wikipedia èdè Gẹ̀ẹ́sì .wikipedia
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Olè àti ọlọ́sà ni gbogbo àwọn tí ó ti wà ṣáájú mi : ṣùgbọ́n àwọn àgùntàngbọ́ ti wọn .àgùntàn
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
“ Lóòótọ́ , lóòótọ́ ni mo wí fún yín , Ẹni tí kò bá gba ẹnu ọ̀nà wọ inú agbo àgùntàn , ṣùgbọ́n ó bá gba ibòmíràn gun òkè , Òun náà ni olè àti ọlọ́sà .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Olè kìí wá bí kò ṣe láti jalè , láti pa , àti láti parun : èmi kí wọn lè ní ìyè , àní kí wọn lè ní i lọ́pọ̀lọpọ̀ .èmi
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Ó sì wí pé , “ Níbo ni ẹ̀yin gbé tẹ́ ẹ sí ? ” Wọ́n fún un pé , “ Olúwa , wá wò ó . ”wọ́n
features...upos=PRON
UD_Yoruba-YTB
Nígbà náà , Jésù dá ọ̀pọ̀ ènìyàn náà dúró . Kò sì jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tẹ̀lé òun lẹ́yìn lọ ilé Jáírù , bí kò ṣe Pétérù , Jákọ́bù àti Jòhánù .òun
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Ó sì kígbe ní ohùn rara wí pé , “ ni ṣe tèmi tìrẹ , Jésù Ọmọ Ọlọ́run Ọ̀ga Ògo ? Mo fi Ọlọ́run bẹ̀ ọ́ má ṣe dá mi ní oró . ”
features...upos=PRON
PronType=Int
UD_Yoruba-YTB
Èyí tí ó wà ní ilé ọnà Met àti èyí tí ó wà ní ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn , méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Wọ́n sì fi í rẹ́rín . Ṣùgbọ́n ó sọ fún gbogbo wọn láti bọ́ sí ìta , ó mú baba àti ìyá ọmọ náà , àti àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ mẹ́ta . Ó sì wọ inú yàrá tí ọmọbìnrin náà gbé dùbúlẹ̀ sí .wọ́n
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Lóòótọ́ ni mo fún un yín , títí ọ̀run òun ayé yóò fi kọjá , àmì kínkínní tí a fi gègé ṣe kan kì yóò parẹ́ kúrò nínú gbogbo òfin tó wà nínú ìwé ofin títí gbogbo rẹ̀ yóò fi wá sí ìmúṣẹ .mo
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Nígbà tí Màríà sì dé ibi tí Jésù , tí ó sì rí i , ó wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀ , ó wí fún un pé , “ Olúwa , ìbáṣe pé ìwọ ti wà níhín-ín , arákùnrin mi kì bá kú . ”Jésù
features...upos=PROPN
UD_Yoruba-YTB
ẹnì kan bá fẹ́ gbé ọ lọ sí ilé ẹjọ́ , tí ó sì fẹ́ gba ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀ , jọ̀wọ́ agbádá rẹ fún un pẹ̀lú .ẹnì
features...upos=PRON
PronType=Ind
UD_Yoruba-YTB
Lẹ́yìn náà ni Ọlọ́run wí pé , “ Ẹ jẹ́ kí a dá ènìyàn ní àwòrán ara wa , gẹ́gẹ́ bí àwa ti rí , kí wọn kí ó jọba lórí ẹja òkun , ẹyẹ ojú ọ̀run , ohun ọ̀sìn , gbogbo ilẹ̀ àti lórí ohun gbogbo ń rìn lórí ilẹ̀ . ”
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Jésùkìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn má ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ . Ó sì wí fún wọn kí wọn fún ọmọbìnrin náà ní oúnjẹ .Jésù
features...upos=PROPN
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run pé “ Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà ní ojú ọ̀run , làti pààlà sí àárin ọ̀sán àti òru , kí wọn ó sì máa wà fún àmì láti mọ àwọn àsìkò , àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún ,ọlọ́run
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
jọ̀wọ́ ẹ kọ́kọ́ wọ ojúewé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ àyọkà náà , bóyá ọ̀rọ̀ ùnlọ nípa rẹ̀ .
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
èmi kò bá ṣe iṣẹ́ Baba mi , ẹ má ṣe gbà mí gbọ́ .èmi
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Nígbà náà , Jésù dá ọ̀pọ̀ ènìyàn náà dúró . Kò sì jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tẹ̀lé òun lẹ́yìn lọ ilé Jáírù , bí kò ṣe Pétérù , Jákọ́bù àti Jòhánù .ẹnikẹ́ni
features...upos=PRON
PronType=Ind
UD_Yoruba-YTB
Ojú ewé yìí kúkurú : Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà jẹ́ Ojú ewé tó tọ́ka sí ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà .ewé
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Nígbà tí àwọn Júù tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ nínú ilé , tí wọ́n ń tù ú nínú rí Màríà tí ó dìde kánkán , ó sì jáde , wọ́n tẹ̀lé , wọ́n ṣebí ó ń lọ sí ibojì láti sọkún níbẹ̀ .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Irú àwòrán yìí kò wọ́pọ̀ ní iṣẹ́ ọnà ilẹ̀ Benin , àti pé ipò Idia , tí iṣẹ̀ṣe àwọn Edo mọ̀ sí " obìnrin kan ṣoṣo tó lọ sógun " , ó da yàtọ̀ , tí wọ́n sí dá oyèIyoba tàbí Ìyá Olori ̀́n sílẹ̀ fun Ìwérí rẹ̀ jẹ́ ara irú irun tí wọ́n ń pè ní ẹnu àparò , tí a lè rí dáadára ní àfihàn orí edẹ Olorì Idia .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò gbàgbọ́ , nítorí ẹ̀yin kò sí nínú àwọn àgùntàn mi , gẹ́gẹ́ bí mo fún yín .mo
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Àwọn Júù sì tún he òkúta , láti sọ lù ú .Júù
features...upos=PROPN
UD_Yoruba-YTB
Nígbà tí ó sì ti wí èyí tán , ó lọ , ó sì pe Màríà arábìnrin rẹ̀ sẹ́yìn wí pé , “ Olùkọ́ , ó sì ń pè ọ́ . ”olùkọ́
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Ṣùgbọ́n alágbàṣe , kìí ṣe olùṣọ́ àgùntàn , ẹni tí àwọn àgùntàn kìí ṣe tirẹ̀ , ó rí ìkokò ń bọ̀ , ó sì fi àgùntàn sílẹ̀ , ó sì fọ́n wọn ká kiri .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run sì wí pé “ Jẹ́ kí òfurufú kí ó ní àárin àwọn omi láti pààlà sí àárin àwọn omi . ”òfurufú
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Èmiyọ̀ nítorí yín , tí èmi kò sí níbẹ̀ , Kí ẹ le gbàgbọ́ ; ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí a lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ .èmi
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Ìwérí rẹ̀ ó rẹwà àti ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ̀ bí ìlẹ̀kẹ̀ roboto ( " ọlà " ) , tí wọ́n fún ìya wa olorì láàfàní láti máa wọ̀ , léyí tí ó jẹ́ pé olóyè ni ówà fún .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́runṣe wọ́n lọ́jọ̀ sí ojú ọ̀run láti máa tan ìmọ́lẹ̀ si orí ilẹ̀ ,ọlọ́run
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn : ṣùgbọ́n òye ohun tí nǹkan wọ̀nyí jẹ́ tí ó ń sọ fún wọn kò wọn .òye
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Fún àpẹrẹ , nọ́mbà gidi nìkan kò ojúùtú fún ìdọ́gba aljebra alápọ̀ọ́nlépúpọ̀ ( polynomial ) pẹ̀lú nọ́mbà àfise gidi ( coefficient ) , sùgbọ̀n àwọn nọ́mbà tósòro ní .nọ́mbà
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Ìmúlò yìí ṣe àpèjúwe bí a ṣe lè máa mú ìdàgbàsókè bá àwọn Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà .a
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Èyí ó ní ilé ọnà Met àti èyí tí ó wà ní ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn , méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Ó dàbí wípé ní bí ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n gbẹ́ àwọn Ìbòjú méjèèjì , bóya ní ọdún 1520 , nígbà tí Olorì Idia , ìyá ọba Oba Esigie , jẹ́ aládájọ́ ní ilé ẹjọ́ ti Benin .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Lọ́gán , Jésù sì mọ̀ nínú ara rẹ̀ pé agbára jáde lára òun . Ó yípadà láàrin ọ̀pọ̀ ènìyàn , ó sì béèrè , “ Ta ni ó fi ọwọ́ kan aṣọ mi ? ”ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Àwọn àpẹẹrẹ rẹ̀ lórí àkọ́lé kan náà ní Seattle Art Museum àti Linden Museum , tí ìkan ná sì wà ní ilé ibi tí wọ́n kò gba òpò eniyan láyè láti wọ̀ , gbogbo rẹ̀ ní wọ́n kó nígbà ìwádí lọ sí ìlú Benin ní ọdún 1897 .àpẹẹrẹ
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi , mo sì mú - un dákẹ́jẹ́ẹ́ , bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú : ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú .a
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè , àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá .ẹgbẹ́
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Èmi ni ìlẹ̀kùn : bí ẹnìkan bá bá ọ̀dọ̀ mi wọlé , Òun ni a ó gbà là , yóò wọlé , yóò sì jáde , yóò sì rí koríko .ẹnìkan
features...upos=PRON
PronType=Ind
UD_Yoruba-YTB
Nígbà náà ni Jésù tún kérora nínú ara rẹ̀ , ó sí ibojì , ó sì jẹ́ ihò , a sì gbé òkúta lé ẹnu rẹ̀ .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Ẹ le wá àkọlé ojúewé yìí nínú àwọn ojúewé mìíràn , tàbí wá àwọn àkọọ́lẹ̀ tó bámu , sùgbọ́n àṣẹ láti ṣ' ẹ̀dá ojúewé yìí .
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
T' óbá sepé àsìsegbé yin dé bi , ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn .àsìse
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
O órúkọ dabí fèrèsé ó fi ÀṢÀ, Èsìn , Iṣé àti ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá hàn .
features...upos=PRON
PronType=Rel
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run sì wí pé , “ Kí ilẹ̀ kí ó ohun alààyè jáde ní onírúurú wọn : ẹran ọ̀sìn , àwọn ohun afàyàfà àti àwọn ẹran inú igbó , ọ̀kọ̀ọ̀kan ní irú tirẹ̀ . ” Ó sì rí bẹ́ẹ̀ .ilẹ̀
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Nígbà tí àwọn Júù tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ nínú ilé , tí wọ́n ń tù ú nínú rí Màríà tí ó dìde kánkán , tí ó sì jáde , wọ́n tẹ̀lé , wọ́n ṣebí ó ń lọ sí ibojì láti sọkún níbẹ̀ .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Bí ẹ̀yin bá fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn yín nìkan , èrè kí ni ẹ̀yin ní ? Àwọn agbowó - òde kò ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ?agbowó
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB
Lóòótọ ni mo wí fún ọ , ìwọ kì yóò jáde kúrò níbẹ̀ títítí ìwọ yóò fi san ẹyọ owó kan tí ó kù .ìwọ
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà nígbà tí Jésù dé , ó rí i pé a ti tẹ́ ẹ sínú ibojì ní ijọ́ mẹ́rin ná ,a
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB
Ó wọ inú ilé lọ , Ó sì bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ , ó béèrè pé , “ Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń sọkún tí ẹ sì ń pohunréré ẹkún ? Ọmọbìnrin náà kò , ó sùn lásán ni . ”ọmọbìnrin
features...upos=NOUN
UD_Yoruba-YTB