Example items (sample of 50)

sen_strnsubj_formnsubj_featuresAux_formAux_featurestreebank_link
Tí ẹ kò bá ní àkópamọ́ , le dá ìkan ; lẹ́yìn ọjọ́ 4 àti àtúnṣe 10 , ẹ ó le ṣàtúnṣe àwọn ojúewé àbò díẹ̀ .
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
le
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Fún àpẹrẹ , 3 + 2i jé nọ́mbà tósòro , pẹ̀lú apá gidi to jẹ 3 ati apá tíkòsi´ to jẹ 2 .apá
features...upos=NOUN
jẹ
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
“ Ẹ̀yin ti gbọ́ bí a ti wí fún àwọn ará ìgbàani pé ; ‘ Ìwọ kò gbọdọ̀ búrá èké bí kò ṣe pé kí ìwọ ó mú ìbúra rẹ̀ sí Olúwa ṣẹ . ’ìwọ
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Láyé àtijọ́ ọjọ́ keje ní wọ́n máa ń sọ ọmọ obìnrin ní órúkọ nígbà tí tọmọ kùnrin sì jẹ́ ọjọ́ kẹsàn - án èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú èrò àti ìgbàgbọ́ wọn pé eegun méje ni obìnrin ní nígbà tí tọkùnrin jẹ́ mẹ́sàn-án .obìnrin
features...upos=NOUN
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run súre fún wọn , ó sì wí pé , “ Ẹ máa bí sí i , máa pọ̀ sí i , ẹ kún inú omi òkun , kí àwọn ẹyẹ náà sì máa pọ̀ sí i ní orí ilẹ̀ . ”
features...upos=PRON
Person=2
PronType=Prn
máa
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Alábùkún - fún ni àwọn ẹni tí a ṣe inúnibíni sí , nítorí tí wọ́n jẹ́ olódodo nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run .wọ́n
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Iyọ̀ , Omi , abbl láti jẹ́ kí ọmọ yìí mọ bí ayé se rí wọn yóò fí gbogbo ohun tí a kà sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu wò , wọ́n sì máa ń wọ́n omi sí ọmọ yìí lára tàbí kí wọ́n da omi sí orí páànù kí wọn ó wá jẹ́ kí ó kán si ọmọ yìí lára .wọn
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
yóò
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Èmiti mọ̀ pé , ìwọ a máa gbọ́ ti èmi nígbà gbogbo : ṣùgbọ́n nítorí ìjọ ènìyàn tí ó dúró yìí ni mo ṣe wí i , kí wọn baà lè gbàgbọ́ pé ìwọ ni ó rán mi . ”èmi
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
ti
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Tí ẹ bá ṣàkíyèsí àsìṣe tàbí ẹ ní àbá fún àtúnṣe , le tọrọ àtúnṣe , nípa títẹ klik sí àjápọ̀ ìsàlẹ̀ , kí ẹ sì tẹ̀lẹ́ àwọn ìlànà ibẹ̀ .
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
le
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín , ṣe búra rárá , : ìbáà ṣe ìfi - ọ̀run - búra , nítorí ìtẹ́ Ọlọ́run ni .
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Irú àwòrán yìí kò wọ́pọ̀ ní iṣẹ́ ọnà ilẹ̀ Benin , àti pé ipò Idia , tí iṣẹ̀ṣe àwọn Edo mọ̀ sí " obìnrin kan ṣoṣo tó lọ sógun " , tí ó da yàtọ̀ , tí wọ́n sí dá oyèIyoba tàbí Ìyá Olori ̀́n sílẹ̀ fun Ìwérí rẹ̀ jẹ́ ara irú irun wọ́n ń pè ní ẹnu àparò , tí a lè rí dáadára ní àfihàn orí edẹ Olorì Idia .
features...upos=PRON
PronType=Rel
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà ni Baba mi ṣe fẹ́ràn mi , nítorí tí mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀ , kí èmi tún gbà á .èmi
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tó dára jùlọ fún 2001 ní City People Awards , ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà .ìkan
features...upos=NOUN
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run sì wí pé “ Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà ní ojú ọ̀run , làti pààlà sí àárin ọ̀sán àti òru , wọn ó sì máa wà fún àmì láti mọ àwọn àsìkò , àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún ,wọn
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=2+
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà àwọn Júù wí pé , “ Sá wò ó bí ó ti fẹ́ràn rẹ̀ tó ! ”ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
ti
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Láyé àtijọ́ ọjọ́ keje ní wọ́n máa ń sọ ọmọ obìnrin ní órúkọ nígbà tí tọmọ kùnrinjẹ́ ọjọ́ kẹsàn - án èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú èrò àti ìgbàgbọ́ wọn pé eegun méje ni obìnrin ní nígbà tí tọkùnrin jẹ́ mẹ́sàn-án .kùnrin
features...upos=NOUN
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
O órúkọ dàbí àmì ìdánimọ̀ tí a fi ń dá ẹnìkọ̀ọ̀kan mọ̀ o órúkọ ló jẹ́ kí á dá Táyé mọ̀ yàtọ̀ sí Kẹ́hìndé , káàkiri àgbáyé ní a sì tí ń lo o órúkọ , ní ọ̀pọ̀ ìgbà o órúkọ sì máa ń fi bí ènìyàn ṣe jẹ́ láwùjọ hàn àti wí pe o órúkọ ẹni le buyì fún ènìyàn láwùjọ .a
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=1
PronType=Prs
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run sì dá ẹranko inú igbó àti ẹran ọ̀sìn gbogbo ní irú tirẹ̀ àti gbogbo ohun alààyè ń rìn ní ilẹ̀ ní irú tirẹ̀ . Ọlọ́run sì rí i pé ó dára .
features...upos=PRON
PronType=Rel
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú , ībòjú kékeré òhún tí kò gígùn rẹ̀ kò ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú , Ọba wọ̀ọ́ sọ́rùn ( tí ó sì maa bá mu ) tàbí bi " ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí " ( èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu ) .ọba
features...upos=NOUN
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nígbà tí Màríà sì dé ibi tí Jésù wà , tí ó sì rí i , ó wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀ , ó wí fún un pé , “ Olúwa , ìbáṣe pé ìwọ ti wà níhín-ín , arákùnrin mi kì bá kú . ”ìwọ
features...upos=PRON
Case=Acc
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
ti
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Níbẹ̀ lówà ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood .
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
ti
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín pé , ‘ ṣe tako ẹni ibi . Bí ẹnì kan bá gbá ọ ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ ọ̀tún , yí ẹ̀rẹ̀kẹ́ òsì sí olúwa rẹ̀ pẹ̀lú .
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Tọ̀sán - tòru láàrin àwọn ibojì àti ní àwọn òkè ni ó máa ń kígbe rara tí ó sì ń fi òkúta ya ara rẹ̀ .òkè
features...upos=NOUN
máa
features...SubjAuxCount=2+
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn : ṣùgbọ́n òye ohun tí nǹkan wọ̀nyí jẹ́ tí ó ń sọ fún wọn kò yé wọn .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Jésù sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ . Ó sì wí fún wọn kí wọn fún ọmọbìnrin náà ní oúnjẹ .wọn
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Bí ẹ̀yin bá fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn yín nìkan , èrè kí ni ẹ̀yin ní ? Àwọn agbowó - òde kò ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ?agbowó
features...upos=NOUN
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ìwérí rẹ̀ tí ó rẹwà àti ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ̀ bí ìlẹ̀kẹ̀ roboto ( " ọlà " ) , tí wọ́n fún ìya wa olorì láàfàní láti máa wọ̀ , léyí tí ó jẹ́ pé olóyè ni ówà fún .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run súre fún wọn , ó sì wí pé , “ Ẹ máa bí sí i , ẹ sì máa pọ̀ sí i , ẹ kún inú omi òkun , àwọn ẹyẹ náà sì máa pọ̀ sí i ní orí ilẹ̀ . ”ẹyẹ
features...upos=NOUN
features...SubjAuxCount=2+
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ṣùgbọ́n bí èmi bá ṣe wọ́n , bí ẹ̀yin kò tilẹ̀ gbà mí gbọ́ , ẹ gbà iṣẹ́ náà gbọ́ : kí ẹ̀yin baà lè mọ̀ , kí ó yé yín pé , Baba wà nínú mi , èmi sì wà nínú rẹ̀ . ”ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ojúewé yìí lọ́wọ́lọ́wọ́ jẹ́ dídá àbò bò díẹ̀ nítoríẹ̀ àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ tí wọ́n ti fẹsẹ̀múlẹ̀ nìkan ni wọ́n le ṣàtúnṣe rẹ̀ .ojúewé
features...upos=NOUN
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Alábùkún - fún ni àwọn aláàánú , nítorí wọn yóò rí àánú gbà .wọn
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
yóò
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà , nígbà tí Mátà gbọ́ pé Jésù ń bọ̀ wá , ó jáde lọ pàdé rẹ̀ : ṣùgbọ́n Màríà jòkó nínú ilé .Jésù
features...upos=PROPN
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
“ Ẹ̀yin ni iyọ̀ ayé . Ṣùgbọ́n bí iyọ̀ bá di òbu ni a ó fi mú un dùn ? Kò tún wúlò fún ohunkóhun mọ́ , bí kò ṣe pé kí a dà á nù , kí ó sì di ohun tí ènìyàn ń fi ẹsẹ̀ tẹ̀ mọ́ ilẹ̀ .
features...upos=PRON
PronType=Int
ó
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Alhaji Lukman Ẹ̀bùn Olóyèdé Ọláìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Igwe jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti òṣèré sinimá àgbéléwò .Alhaji
features...upos=PROPN
Case=Acc
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
jẹ́
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ẹ̀yin ti gbọ́ bí a ti wí fún àwọn ará ìgbàanì pé , ‘ Ìwọ kò gbọdọ̀ pa ènìyàn , ẹnikẹni tí ó bá pa ènìyàn yóò wà nínú ewu ìdájọ́ . ’ẹ̀yin
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=2
PronType=Prs
ti
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
“ Nítorí náà , nígbà tí ìwọń mú ẹ̀bùn rẹ wá ṣíwájú pẹpẹ , bí ìwọ bá sì rántí níbẹ̀ pé arákùnrin rẹ̀ ni ohùn kan nínú sí ọ .ìwọ
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Èmi sì ti mọ̀ pé , ìwọ a máa gbọ́ ti èmi nígbà gbogbo : ṣùgbọ́n nítorí ìjọ ènìyàn tí ó dúró yìí ni mo ṣe wí i , kí wọn baà gbàgbọ́ pé ìwọ ni ó rán mi . ”wọn
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
“ A ti wí pẹ̀lú pé , ‘ Ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ aya rẹ̀ sí ilẹ̀ gbọdọ̀ fún un ní ìwé - ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ . ’ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
gbọdọ̀
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Bákan náà , ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín kí ó mọ́lẹ níwájú ènìyàn , kí wọ́n lè máa rí iṣẹ́ rere yín , kí wọn lè máa yin baba yín ń bẹ ní ọ̀run ní ògo .
features...upos=PRON
PronType=Rel
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nígbà náà , obìnrin náà kún fún ìbẹ̀rù àti ìwárìrì nítorí ó ti mọ ohun ó ṣẹlẹ̀ ní ara òun . Ó sì kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀ , ó sì sọ ohun tí òun ti ṣe .
features...upos=PRON
PronType=Rel
ó
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Àwọn ọmọ - ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún un pé , “ Ìwọ rí ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ó rọ̀gbà yí ọ ká , ìwọ́ sì tún ń bèèrè ẹni tí ó fi ọwọ́ kàn ọ́ ? ”ìwọ́
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Iyọ̀ , Omi , abbl láti jẹ́ kí ọmọ yìí mọ bí ayé se rí wọn yóò fí gbogbo ohun tí a kà sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu wò , wọ́n sì máa ń wọ́n omi sí ọmọ yìí lára tàbí kí wọ́n da omi sí orí páànù kí wọn ó wá jẹ́ó kán si ọmọ yìí lára .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
jẹ́
features...SubjAuxCount=2+
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Bákan náà , ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín kí ó mọ́lẹ níwájú ènìyàn , kí wọ́n lè máa rí iṣẹ́ rere yín , kí wọn máa yin baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ní ògo .wọn
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=2+
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ẹni tí ojú rẹ̀ sì ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpọ́njú lọ́dọ̀ ọ̀pọ̀ àwọn oníṣègùn , tí ó sì ti ná gbogbo ohun tí ó ní , síbẹ̀ kàkà kí ó san , ó ń burú sí i .ẹni
features...upos=PRON
PronType=Ind
ti
features...SubjAuxCount=1
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Àwọn olùtọ́jú ẹran wọ̀nyí sì sá lọ sí àwọn ìlú ńlá àti ìlú kéékèèkéé , wọ́nń tan ìròyìn náà ká bí wọ́n ti ń sáré . Àwọn ènìyàn sì tú jáde láti fojú gán-án-ní ohun náà tí ó sẹlẹ̀ .wọ́n
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ẹni tí ojú rẹ̀ sì ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpọ́njú lọ́dọ̀ ọ̀pọ̀ àwọn oníṣègùn , tí ó sì ti ná gbogbo ohun tí ó ní , síbẹ̀ kàkà kí ó san , ó ń burú sí i .ó
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
ń
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
“ Ẹ̀yin ti gbọ́ bí a ti wí fún àwọn ará ìgbàani pé ; ‘ Ìwọgbọdọ̀ búrá èké bí kò ṣe pé kí ìwọ kí ó mú ìbúra rẹ̀ sí Olúwa ṣẹ . ’ìwọ
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
gbọdọ̀
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
A sọ pé àwón nọ́mbà gidi je nọ́mbà tósòro pelu apá tíkòsi´ tó jé òdo ; eyun pé nọ́mbà gidi a jẹ́ bakanna mọ́ nọ́mbà tósòro a+0i .a
features...upos=PRON
Case=Nom
Number=Plur
Person=1
PronType=Prs
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Nígbà náà , àwọn èrò bẹ̀rẹ̀ sí ní bẹ Jésù ó fi agbégbé àwọn sílẹ̀ .Jésù
features...upos=PROPN
features...SubjAuxCount=1
VerbForm=Fin
UD_Yoruba-YTB
Ihò tí ó wà ní ibi oun ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ àti ibi ọrùn rẹ̀ jẹ́ àpẹẹrẹ ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn tí àwọn ọkùnrin Àgùdà maa ń fi ṣẹ̀ṣọ́ , tí ó sì jẹ́ wípé àwòrán mọ́kànlá bẹ́ẹ̀ wà ní ilé ọnà ìbòjú tí Bìrìtìkó àti pé mẹ́tàlá wà ní ilé ọnà Met tí ó ṣe àfihàn àwọn ọkùnrin Àgùdá tí wọ́n múra bí àwọn ènìyàn dúdú .ọkùnrin
features...upos=NOUN
Person=3
maa
features...SubjAuxCount=2+
Case=Nom
Number=Plur
Person=1
PronType=Prs
UD_Yoruba-YTB