Example items (sample of 50)
| sen_str | Verb_form | Verb_features | nsubj_form | nsubj_features | treebank_link |
|---|---|---|---|---|---|
| A fi àṣẹ lò ó . | fi | features...upos=VERBdeprel=root lemma=fi | a | features...upos=PRONlemma=A deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Shuvra Kar kọ sí oríi Facebook : | kọ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=kọ | Shuvra | features...upos=PROPNlemma=Shuvra deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bẹ́ẹ̀ ni a kì í tan fìtílà tán , kí a sì gbé e sí abẹ́ òṣùnwọ̀n ; bí kò ṣe sí orí ọ̀pá fìtílà , a sì tan ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo ẹni tí ń bẹ nínú ilé . | tan | features...upos=VERBdeprel=root lemma=tan | a | features...upos=PRONlemma=a Case=Nom Number=Plur Person=1 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| ṣùgbọ́n lóde - òní ohun gbogbo ti yí padà àti obìnrin àti ọkùnrin ni wọ́n ń sọ ní órúkọ lọ́jẹ́ kẹjọ . | yí | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=yí | ohun | features...upos=NOUNlemma=ohun deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| 2500 kwanzas ( owó dollar orílẹ̀-èdè US mẹ́jọ ) ni ó jẹ́ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ . | ni | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ni | 2500 | features...upos=NOUNlemma=2500 deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Wọ́n pe ìpolongo wọn ní “Ẹ Yé é Dà Wá" , wọ́n gbà pé ìwà ọ̀dàlẹ̀ jẹ́ ìdí tí ó tọ́ láti máa fìyà jẹ obìnrin . | yé | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=Yé | “ẹ | features...upos=PRONlemma=“ẹ deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Nígbà náà ni wọ́n gbé òkúta náà kúrò ( níbi tí a tẹ́ ẹ sí ) . Jésù sì gbé ojú rẹ̀ sókè , ó sì wí pé , “ Baba , mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ nítorí tí ìwọ gbọ́ tèmi . | gbé | features...upos=VERBdeprel=root lemma=gbé | wọ́n | features...upos=PRONlemma=wọ́n Case=Nom Number=Plur Person=3 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ohun tí ó bá àwọn oníròyìn sọ rè é , gẹ́gẹ́ bí OJÚOLÚWAKÒTÌMÍ OLÚṢÍNÀ ti kọ ọ́ sí ilẹ̀ | kọ | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=kọ | OLÚṢÍNÀ | features...upos=PROPNlemma=OLÚṢÍNÀ deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood . | kópa | features...upos=VERBdeprel=root lemma=kópa | ó | features...upos=PRONlemma=Ó Case=Nom Number=Sing Person=3 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ọlọ́run súre fún wọn , ó sì wí pé , “ Ẹ máa bí sí i , ẹ sì máa pọ̀ sí i , ẹ kún inú omi òkun , kí àwọn ẹyẹ náà sì máa pọ̀ sí i ní orí ilẹ̀ . ” | kún | features...upos=VERBdeprel=conj lemma=kún | ẹ | features...upos=PRONlemma=ẹ deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Láti orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin àgbáyé , igbe ńlá ni ó gba àwọn akọbúlọ́ọ̀gù Zone9 sílẹ̀ lọ́wọ́ ìjọba ilẹ̀ Ethiopia . | ni | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ni | igbe | features...upos=NOUNlemma=igbe deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìwée nì The Status of Nepal’s Birds : The National Red List Series sọ wípé : | sọ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=sọ | The | features...upos=PROPNlemma=The deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bí a bá kà á ní ẹníméjì , ó ti tó ènìyàn 500 tí ó ti ṣe ìrìnàjò náà . | bá | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=bá | a | features...upos=PRONlemma=a deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹnìkan kò gbà á lọ́wọ́ mi , ṣùgbọ́n mo fi í lélẹ̀ , mo sì lágbára láti tún gbà á . Àṣẹ yìí ni mo ti gbà wá láti ọ̀dọ̀ Baba mi . ” | gbà | features...upos=VERBdeprel=parataxis lemma=gbà | mo | features...upos=PRONlemma=mo Case=Nom Number=Sing Person=1 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ní ọdún 2011 , ó lo oṣù méjì ní ẹ̀wọ̀n , àkókò yìí ni ìyàwóo rẹ̀ bí àkọ́bíi rẹ̀ , Khaled . | lo | features...upos=VERBdeprel=root lemma=lo | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn ọmọ ìlú tí wọ́n ń ṣàmúlò ayélujára ti bẹ̀rẹ̀ ìkọkúkọ sórí àwòrán ààrẹ Nkurunziza nínú ìfẹ̀hónúhàn pẹ̀lú àmì ìdámọ̀ : #Nkurunziza àti #Burundi : | ṣàmúlò | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=ṣàmúlò | wọ́n | features...upos=PRONlemma=wọ́n deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Atnaf Berhane rántí wípé òún jẹ ìyà oró di aago méjì òru tí òún padà sí lẹ́yìn oorun díẹ̀ . | padà | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=padà | òún | features...upos=PRONlemma=òún deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìbòo 8,491 tí wọ́n dì fún un ni wọ́n fi yàn án sípò kan nínúu mẹ́jọ tí ó tọ́ sí ìpínlẹ̀ Roraima tí ó ti wá . | fi | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=fi | wọ́n | features...upos=PRONlemma=wọ́n deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìtàn náà jọ ti Omar Juma fúnra rẹ̀ : | jọ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=jọ | ìtàn | features...upos=NOUNlemma=Ìtàn deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn àti ẹgbẹ́ ajàfómìnira ti sọ̀rọ̀ síta láti gbèjà Abubacar tí wọ́n sọ pé mímú tí wọ́n mú un àti àtìmọ́lée rẹ̀ ti dẹ́rùba òmìnira ẹni láti sọ̀rọ̀ . | mú | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=mú | wọ́n | features...upos=PRONlemma=wọ́n deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jíìpù tí wọ́n ní kí Ayọ̀kúnlé fọ̀ ni ó jí gbé , ni ọwọ́ bá tẹ̀ ẹ́ | tẹ̀ | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=tẹ̀ | ọwọ́ | features...upos=NOUNlemma=ọwọ́ deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ṣùgbọ́n èmi wí fún un yín pé , ẹnikẹ́ni tí ó bínú sí arákùnrin rẹ̀ yóò wà nínú ewu ìdájọ́ . Ẹnikẹ́ni ti ó ba wí fun arakùnrin rẹ̀ pé , ‘ Ráákà ’ yóò fara hàn níwájú Sahẹ́ńdìrì ; ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá wí pé ‘ Ìwọ wèrè ! ’ yóò wà nínú ewu iná ọ̀run àpáàdì . | wí | features...upos=VERBdeprel=root lemma=wí | èmi | features...upos=PRONlemma=èmi Case=Nom Number=Sing Person=1 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ọ̀kan nínú àwọn olórí sínágọ́gù tí à ń pè ni Jáírù wá sọ́dọ̀ Jésù , nígbà tí ó sì rí i , ó wólẹ̀ níwájú rẹ̀ . | wólẹ̀ | features...upos=VERBdeprel=conj lemma=wólẹ̀ | ó | features...upos=PRONlemma=ó Case=Nom Number=Sing Person=3 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ìṣọmọlí órúkọ láàárín àwọn Yorùbá dàbí ìgbà tí a ń ṣe ọdún ní torí pé tọmọ , taya , tẹbí , tará , tìyekan àti àwọn alábáse gbogbo ní yóò pésẹ̀ sí ibẹ̀ . | dàbí | features...upos=VERBdeprel=root lemma=dàbí | órúkọ | features...upos=NOUNlemma=órúkọ deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Àná , ọjọ́ Sátidé ni Janet jáde ní ayé ní tiẹ̀ | ni | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ni | àná | features...upos=NOUNlemma=Àná deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn kan ń gbà o , ṣùgbọ́n àwa kò gbà á ní ọwọ́ ẹnikẹ́ni | gbà | features...upos=VERBdeprel=root lemma=gbà | àwa | features...upos=PRONlemma=àwa deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bí a ṣe ń ṣe ìṣọmọlí órúkọ yàtọ̀ láti idílẹ́ sí ìdílé ṣùgbọ́n ní ọjọ́ ìṣọmọlí órúkọ yìí àgbà ilé lóbìnrin yóò gbé ọmọ yìí lọ́wọ́ yóò sì fí ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ilẹ̀ . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ṣe | a | features...upos=PRONlemma=a Case=Nom Number=Plur Person=1 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood . | bẹ̀rẹ̀ | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=bẹ̀rẹ̀ | tó | features...upos=PRONlemma=tó Case=Nom Number=Sing Person=3 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ìwérí rẹ̀ tí ó rẹwà àti ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ̀ bí ìlẹ̀kẹ̀ roboto ( " ọlà " ) , tí wọ́n fún ìya wa olorì láàfàní láti máa wọ̀ , léyí tí ó jẹ́ pé olóyè ni ówà fún . | rẹwà | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=rẹwà | tí | features...upos=PRONlemma=tí PronType=Rel deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ìrí-bá-kan-náà , Danjuma fi ariwo ta nípa ète bí àwọn “ọlọ́pàá àti ológun" ṣe ń gbìmọ̀pọ̀ láti ṣe ẹ̀rú nínú ìbò ọdún 2019 . | fi | features...upos=VERBdeprel=root lemma=fi | Danjuma | features...upos=PROPNlemma=Danjuma deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ilẹ̀ sì hù ọ̀gbìn : ewéko tí ó ń so èṣo ní irú tirẹ̀ , àti igi tí ń so èṣo , tí ó ní irúgbìn nínú ní irú tirẹ̀ . Ọlọ́run sì ri pé ó dára . | so | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=so | tí | features...upos=PRONlemma=tí PronType=Rel deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín pé , ẹ fẹ́ràn àwọn ọ̀ta yín kí ẹ sì gbàdúrà fún àwọn tí ń ṣe inúnibíni sí yín , | fẹ́ràn | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=fẹ́ràn | ẹ | features...upos=PRONlemma=ẹ Case=Nom Number=Plur Person=2 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ilé-iṣẹ́ ti sọ ayẹyẹ àjọyọ̀ àjọ̀dún Òyìnbó di èèwọ̀ . | sọ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=sọ | ilé-iṣẹ́ | features...upos=NOUNlemma=Ilé-iṣẹ́ deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìloro àbáwọlé ìwọ̀-oòrùn-un ààfin náà nìkan ni ó ṣì ń dúró . | dúró | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=dúró | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Níbàyìí , àwọn orílẹ̀-èdè Ilẹ̀-adúláwọ̀ níṣẹ́ láti ṣe sí ètò lílọ-àti-bíbọ̀ àwọn ọmọadúláwọ̀ . | níṣẹ́ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=níṣẹ́ | orílẹ̀-èdè | features...upos=NOUNlemma=orílẹ̀-èdè deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Nítorí ohun tí ó jẹ́ kí ó ṣeé ṣe ò ju bí Buhari ṣe fi ọwọ́ wẹ ọwọ́ pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣèlú ìgbàanì Action Congress of Nigeria (ACN) ti Bọ́lá Tinubu . | fi | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=fi | Buhari | features...upos=PROPNlemma=Buhari deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jésù wí fún un pé , “ Èmi kò ti wí fún ọ pé , bí ìwọ bá gbàgbọ́ , ìwọ ó rí ògo Ọlọ́run ? ” | wí | features...upos=VERBdeprel=root lemma=wí | Jésù | features...upos=PROPNlemma=jésù deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Mátà wí fún un pé , “ Mo mọ̀ pé yóò jíǹde ní àjíǹde ìkẹyìn . ” | wí | features...upos=VERBdeprel=root lemma=wí | Mátà | features...upos=PROPNlemma=mátà deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Àwọn tí ó f’ara kááṣá wọ̀nyìí ni àwọn Adivasis , Harijans àti Dalits . | ni | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ni | àwọn | features...upos=PRONlemma=Àwọn deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bákan náà , ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín kí ó mọ́lẹ níwájú ènìyàn , kí wọ́n lè máa rí iṣẹ́ rere yín , kí wọn lè máa yin baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ní ògo . | mọ́lẹ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=mọ́lẹ | ìmọ́lẹ̀ | features...upos=NOUNlemma=ìmọ́lẹ̀ deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín pé , ‘ Ẹ má ṣe tako ẹni ibi . Bí ẹnì kan bá gbá ọ ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ ọ̀tún , yí ẹ̀rẹ̀kẹ́ òsì sí olúwa rẹ̀ pẹ̀lú . | gbá | features...upos=VERBdeprel=parataxis lemma=gbá | ẹnì | features...upos=PRONlemma=ẹnì PronType=Ind deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| À ń fẹ́ aṣojú tí yóò rí i wípé à ń rí ẹtọ wa gbà lóòrèkóòrè . | rí | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=rí | à | features...upos=PRONlemma=à deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwa náà ní láti di aṣíwájú fún ara wa… | ní | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ní | àwa | features...upos=PRONlemma=Àwa deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìtakò jẹ́ dandanàndan nínú ìjọba tiwantiwa tí ó yé kooro . | yé | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=yé | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Èmi sì ti mọ̀ pé , ìwọ a máa gbọ́ ti èmi nígbà gbogbo : ṣùgbọ́n nítorí ìjọ ènìyàn tí ó dúró yìí ni mo ṣe wí i , kí wọn baà lè gbàgbọ́ pé ìwọ ni ó rán mi . ” | gbàgbọ́ | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=gbàgbọ́ | wọn | features...upos=PRONlemma=wọn Case=Nom Number=Plur Person=3 PronType=Prs deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Kò sí ẹ̀rí tí ó fi ẹsẹ̀ rinlẹ̀ . | fi | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=fi | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Gbogbo obìnrin Azerbaijan ni ó fẹ́ fi ìwà jọ ìyá àgbà Saray . | ni | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ni | gbogbo | features...upos=NOUNlemma=Gbogbo deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àìmọye àwọn ènìyàn tí ó wà nínú ìrìnàjò afẹ́ náà jẹ́ àgbàlagbà . | wà | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=wà | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jésù dá wọn lóhùn pé , “ A kò ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín pé , ‘ Mo ti wí pé , Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́ ’ ? | dá | features...upos=VERBdeprel=root lemma=dá | Jésù | features...upos=PROPNlemma=Jésù deprel=nsubj | UD_Yoruba-YTB |
| Kí ni ó fa àìlera Túndé | fa | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=fa | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=nsubj | UD_Yoruba-AfriSUD |