Example items (sample of 50)

sen_strAux_formAux_featuresnsubj_formnsubj_featurestreebank_link
Ọ̀rọ̀ sísọ lórí ayélujára ti ń rí ìfúnpa láti ọwọ́ ìjọba díẹ̀ díẹ̀ .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=2+
ọ̀rọ̀
features...upos=NOUN
lemma=Ọ̀rọ̀
Person=3
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Muntasir Mamun ti kọ àìmọye ìwé lóríi ìtàn-ìṣẹ̀lẹ̀-àtẹ̀yìnwá àti àjogúnbá ìlúu Dhaka .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=1
Muntasir
features...upos=PROPN
lemma=Muntasir
Person=3
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Jésù sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn má ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ . Ó sì wí fún wọn kí wọn fún ọmọbìnrin náà ní oúnjẹ .má
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=má
SubjAuxCount=1
wọn
features...upos=PRON
lemma=wọn
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Láyé àtijọ́ ọjọ́ keje ní wọ́n máa ń sọ ọmọ obìnrin ní órúkọ nígbà tí tọmọ kùnrin sì jẹ́ ọjọ́ kẹsàn - án èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú èrò àti ìgbàgbọ́ wọn pé eegun méje ni obìnrin ní nígbà tí tọkùnrin jẹ́ mẹ́sàn-án .jẹ́
features...upos=AUX
deprel=cop
lemma=jẹ́
SubjAuxCount=1
obìnrin
features...upos=NOUN
lemma=obìnrin
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Kò pẹ́ lẹ́yìn tí ó jáwé olúborí nínú ìdìbò 2018 , Bolsonaro tún mú ọ̀rọ̀ Raposa Terra do Sol bọnu gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ agbègbè ìbílẹ̀ tí ó yẹ kí àwọn jẹ àǹfààní ètò ọrọ̀-ajée rẹ̀ .kò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=Kò
SubjAuxCount=2+
Bolsonaro
features...upos=PROPN
lemma=Bolsonaro
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ní orí ìlànà ètò ìpàdé àkọ́kọ́ ìgbìmọ̀ọ Tanzania ọdún-un 2019 ni ìdámọ̀ràn àtúnṣe sí Òfin Ẹgbẹ́ Òṣèlú , tí ó ti ní àríyànjiyàn lemọ́lemọ́ nínúu ìṣèlú tí nǹkan kò ṣe ẹnu re .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ó sì ń fa àmì ìfòyà .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=Ó
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ọ̀kan nínú ìkìlọ̀ náà (ọ̀tún) ń tọ́ka sí òfin “Ìmọ̀ràn" ó sì rọ olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ láti kọ àyájọ́ tí ó fi ara jọ ti Òyìnbó sílẹ̀ .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=2+
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Àwọn Àgùdà jẹ́ oníṣòwò pẹ̀lú àwọn Benin nígbàyẹn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ , ó jẹ́ àpẹrẹ́ àjọṣepọ̀ láàrin omi àti ilẹ̀ .jẹ́
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=jẹ́
SubjAuxCount=1
Àgùdà
features...upos=PROPN
lemma=Àgùdà
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
A máa tẹ̀síwajú láti béèrè fún àwùjọ tí a ti lè gbáyé pẹ̀lú ààbò tó péye .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=2+
a
features...upos=PRON
lemma=a
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Àti pé ayé ìrora ni wọ́n ń gbé , wọ́n sì ń tiraka láti gbé .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
wọ́n
features...upos=PRON
lemma=wọ́n
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Iyọ̀ , Omi , abbl láti jẹ́ kí ọmọ yìí mọ bí ayé se rí wọn yóò fí gbogbo ohun tí a kà sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu wò , wọ́n sì máa ń wọ́n omi sí ọmọ yìí lára tàbí kí wọ́n da omi sí orí páànù kí wọn ó wá jẹ́ kí ó kán si ọmọ yìí lára .jẹ́
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=jẹ́
SubjAuxCount=2+
ọmọ
features...upos=NOUN
lemma=ọmọ
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Lóòótọ ni mo wí fún ọ , ìwọ kì yóò jáde kúrò níbẹ̀ títítí ìwọ yóò fi san ẹyọ owó kan tí ó kù .yóò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=yóò
SubjAuxCount=1
ìwọ
features...upos=PRON
lemma=ìwọ
Case=Nom
Number=Sing
Person=2
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Iyọ̀ , Omi , abbl láti jẹ́ kí ọmọ yìí mọ bí ayé se rí wọn yóò fí gbogbo ohun tí a kà sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu wò , wọ́n sì máa ń wọ́n omi sí ọmọ yìí lára tàbí kí wọ́n da omi sí orí páànù kí wọn ó wá jẹ́ kí ó kán si ọmọ yìí lára .yóò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=yóò
SubjAuxCount=1
wọn
features...upos=PRON
lemma=wọn
Case=Acc
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Ní iwájú wọn ni wọ́n ti pa á .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=1
wọ́n
features...upos=PRON
lemma=wọ́n
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Alábùkún - fún ni àwọn tonílàjà , nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè wọ́n .ó
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ó
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
SubjAuxCount=2+
ọmọ
features...upos=NOUN
lemma=ọmọ
Person=3
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Kíni mo le ṣe ?le
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=lè
SubjAuxCount=1
mo
features...upos=PRON
lemma=mo
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Àwọn òbí gbọdọ̀ mọ pé kì í ṣe ọ̀fẹ́ ni àwọn ọmọ wọn máa kẹ́kọ̀ọ́ , kò rí bẹ̀ẹ́ okì
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kì
SubjAuxCount=2+
í
features...upos=PRON
lemma=í
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nígbà náà , àwọn èrò bẹ̀rẹ̀ sí ní bẹ Jésù pé kí ó fi agbégbé àwọn sílẹ̀ .kí
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kí
SubjAuxCount=1
Jésù
features...upos=PROPN
lemma=Jésù
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Ó tó bíi ẹgbẹ̀rún márùn-ún ènìyàn tí ó ń gbé jákèjádò Ilẹ̀ Ìbílẹ̀ tí fífẹ̀ reluwé kó bá .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ọnà ara ilé náà kọjá àfẹnusọ tí a kò leè rí lára àwọn ilé mìíràn ní àwọn agbègbè àtijọ́ọ Dhaka .kò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kò
SubjAuxCount=2+
a
features...upos=PRON
lemma=a
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀ , Jésù rí i pé gbogbo nǹkan ti dàrú . Ilé kún fún àwọn tí ń sọkún , àti àwọn tí ń pohùnréré ẹkún .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
tí
features...upos=PRON
lemma=tí
PronType=Rel
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Ọlọ́run sì wí pé , “ Jẹ́ kí omi abẹ́ ọ̀run wọ́ papọ̀ sí ojúkan , kí ilẹ̀ gbígbẹ sì farahàn . ” Ó sì rí bẹ́ẹ̀ .kí
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kí
SubjAuxCount=1
ilẹ̀
features...upos=NOUN
lemma=ilẹ̀
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Ègbè tí àwọn òǹwòran lè kọ tẹ̀lé orin , ní ìdásí àti ìdáhùn tíì ṣe àṣà calinda , tí calypso — àti àdàlù ìgbàlódé , soca — ti wáyé .lè
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=lè
SubjAuxCount=1
òǹwòran
features...upos=NOUN
lemma=òǹwòran
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nígbà náà ni Jésù tún kérora nínú ara rẹ̀ , ó wá sí ibojì , ó sì jẹ́ ihò , a sì gbé òkúta lé ẹnu rẹ̀ .jẹ́
features...upos=AUX
deprel=cop
lemma=jẹ́
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú , ībòjú kékeré òhún tí kò gígùn rẹ̀ kò ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú , Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn ( tí ó sì maa bá mu ) tàbí bi " ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí " ( èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu ) .jẹ́
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=jẹ́
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà , nígbà tí Mátà gbọ́ pé Jésù ń bọ̀ wá , ó jáde lọ pàdé rẹ̀ : ṣùgbọ́n Màríà jòkó nínú ilé .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
Jésù
features...upos=PROPN
lemma=jésù
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Jésù kò tíì wọ ìlú , ṣùgbọ́n ó wà ní ibi kan náà tí Mátà ti pàdé rẹ̀ .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=1
Mátà
features...upos=PROPN
lemma=mátà
Person=3
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Ọjà Kàtàngòwá máa parí ní àìpẹ́ , a ò ní fi ohunkóhun dun ẹnìkan -máa
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=máa
SubjAuxCount=2+
a
features...upos=PRON
lemma=a
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Èmi sì ní àwọn àgùntàn mìíràn , tí kìí ṣe agbo yìí : àwọn ni èmi yóò mú wá pẹ̀lú , wọn ó sì gbọ́ ohùn mi ; wọn ó sì jẹ́ agbo kan , olùsọ́ - àgùntàn kan .jẹ́
features...upos=AUX
deprel=cop
lemma=jẹ́
SubjAuxCount=1
wọn
features...upos=PRON
lemma=wọn
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Kí ẹ̀yin lè jẹ́ ọmọ Baba yín bi ń bẹ ní ọ̀run . Ó mú kí oòrùn rẹ̀ ràn sí ara ènìyàn búburú àti ènìyàn rere , ó rọ̀jò fún àwọn olódodo àti fún àwọn aláìṣòdodo .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
ọmọ
features...upos=NOUN
lemma=ọmọ
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Ó sì bẹ̀ ẹ́ gidigidi pé , “ Ọmọbìnrin mi wà lójú ikú , mo bẹ̀ ọ́ , wá fi ọwọ́ rẹ lé e , kí ara rẹ̀ lè dá , kí ó sì yè . ”lè
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=lè
SubjAuxCount=1
ara
features...upos=PRON
lemma=ara
PronType=Emp
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Agbo ẹlẹ́dẹ̀ ńlá kan sì ń jẹ lẹ́bàá òké .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
ẹlẹ́dẹ̀
features...upos=NOUN
lemma=ẹlẹ́dẹ̀
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Èké àti irọ́ wọn ti sú àwọn èèyàn .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=1
èké
features...upos=NOUN
lemma=Èké
Person=3
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nígbà náà ni ẹ̀mí àìmọ́ náà bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ Jésù gidigidi , kí ó má ṣe rán àwọn jáde kúrò ní agbègbè náà .má
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=má
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
Case=Nom
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
100 ọjọ́ fún Alaa : Ẹbí ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọ Íjípìtì ń ka ọjọ́ fún ìdásílẹ̀ẹ rẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀nń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
ẹbí
features...upos=NOUN
lemma=Ẹbí
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ìwọ́de afẹ́ àwọn abódiakọ-akọ́diabo àkọ́kọ́ lè tú èrò nípa wọn ní Pakístánì kálè
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=lè
SubjAuxCount=1
ìwọ́de
features...upos=NOUN
lemma=Ìwọ́de
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Àwọn méjèèjì ti ń figagbága nínú ìbò Nàìjíríà ní ọjọ́ tí ó ti pẹ́ .ti
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ọ̀gágun tí ó ti jagun fẹ̀yìntì kì í sinmi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríàkì
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kì
SubjAuxCount=1
ọ̀gágun
features...upos=NOUN
lemma=Ọ̀gágun
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Láti ilẹ̀ , ìtàkùrọ̀sọ lórí ayélujára ní Nàìjíríà kò lọ láìsí ìkórìíra .kò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kò
SubjAuxCount=1
ìtàkùrọ̀sọ
features...upos=NOUN
lemma=ìtàkùrọ̀sọ
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ní agbo ọ̀rẹ́ẹ wa , àgọ́ alòdìsí àjọ̀dún Òyìnbó àti alòdìsí alòdìsí àjọ̀dún Òyìnbó ń ṣe àríyànjiyàn .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
alòdìsí
features...upos=NOUN
lemma=alòdìsí
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ohun tí a máa ṣe kò le yàtọ̀ sí ohun tí a ṣe ní àsìkò Èbólà , ẹ rántí pé Èbólà gan-an tún pa ènìyàn ju Kòrónà yìí lọkò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kò
SubjAuxCount=2+
ẹ
features...upos=PRON
lemma=ẹ
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Àjọ̀dún Òyìnbó ń bọ̀ lọ́nà dẹ̀dẹ̀ .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
àjọ̀dún
features...upos=NOUN
lemma=Àjọ̀dún
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Kí wọn ó jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ní ojú ọ̀run , láti tan ìmọ́lẹ̀ sí orí ilẹ̀ . ” Ó sì rí bẹ́ẹ̀ .kí
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kí
SubjAuxCount=2+
wọn
features...upos=PRON
lemma=wọn
Case=Nom
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Àwọn àjọ̀dún wọ̀nyí lè mú ìkóúnjẹjẹ gbòòrò , kí ni ó burú nínú ìyẹn?lè
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=lè
SubjAuxCount=2+
kí
features...upos=NOUN
lemma=kí
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ṣùgbọ́n tí ó pa ìdí ọ̀rẹ́ dá sí Yar'Adua lẹ́yìn ìgbátí ó bẹ̀rẹ̀ àìsàn tí kò sì gbé ètò ìṣe ìjọba fún igbákèjì rẹ̀ tii ṣe Goodluck Jónátánì .kò
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=kò
SubjAuxCount=1
ó
features...upos=PRON
lemma=ó
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ilẹ̀ sì hù ọ̀gbìn : ewéko tí ó ń so èṣo ní irú tirẹ̀ , àti igi tí ń so èṣo , tí ó ní irúgbìn nínú ní irú tirẹ̀ . Ọlọ́run sì ri pé ó dára .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
tí
features...upos=PRON
lemma=tí
PronType=Rel
deprel=nsubj
UD_Yoruba-YTB
Bí àwọn iléeṣẹ́ ṣe ń ṣiṣẹ́ , ìyá ń ké .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
ìyá
features...upos=NOUN
lemma=ìyá
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Èyí kéyìí tí ò báà jẹ́ , òòsà ìwé-ìrìnnà ń béèrè ẹbọ síi , tí kò sì yé gbẹbọ .ń
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ń
SubjAuxCount=1
òòsà
features...upos=NOUN
lemma=òòsà
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ilé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ orin kíkọ kan ṣoṣo ní Zanzibar ti fẹ́ di títì pati
features...upos=AUX
deprel=aux
lemma=ti
Case=Nom
Number=Sing
Person=1
SubjAuxCount=2+
ilé
features...upos=NOUN
lemma=Ilé
Person=3
deprel=nsubj
UD_Yoruba-AfriSUD