Example items (sample of 50)

sen_strVerb_formVerb_featuresobj_formobj_featurestreebank_link
Ohun tí ó mú èyí bani nínú jẹ́ jù ni fún ẹni láti rí ikú tí ó pa ẹ̀gbọ́n ẹni .pa
features...upos=VERB
deprel=acl
lemma=pa
ẹ̀gbọ́n
features...upos=NOUN
lemma=ẹ̀gbọ́n
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nígbà tí Màríà sì dé ibi tí Jésù wà , tí ó sì rí i , ó wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀ , ó wí fún un pé , “ Olúwa , ìbáṣe pé ìwọ ti wà níhín-ín , arákùnrin mi kì bá kú . ”dé
features...upos=VERB
deprel=advcl
lemma=dé
ibi
features...upos=NOUN
lemma=ibi
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
inúu wa dùn nítorí wípé a fún àwọn ènìyàn mìíràn ní ìmísí ni ."ní
features...upos=VERB
deprel=aux
lemma=ní
ìmísí
features...upos=NOUN
lemma=ìmísí
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Wọ́n sì fi í rẹ́rín . Ṣùgbọ́n ó sọ fún gbogbo wọn láti bọ́ sí ìta , ó mú baba àti ìyá ọmọ náà , àti àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ mẹ́ta . Ó sì wọ inú yàrá tí ọmọbìnrin náà gbé dùbúlẹ̀ sí .rẹ́rín
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=rẹ́rín
í
features...upos=PRON
lemma=í
Case=Acc
Number=Sing
Person=3
PronType=Prs
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà àwọn Júù wá dúró yí i ká , wọ́n sì wí fún un pé , “ Ìwọ ó ti mú wa ṣe iyèméjì pẹ́ tó ? Bí ìwọ bá ni Kírísítì náà , wí fún wa gbangba . ”mú
features...upos=VERB
deprel=ccomp
lemma=mú
wa
features...upos=PRON
lemma=wa
Case=Acc
Number=Plur
Person=1
PronType=Prs
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Olórí ni wa , aronújinlẹ̀ ni wa , ọlọ́pọlọ pípé ni wa , onímọ̀ ni wa .ni
features...upos=VERB
deprel=aux
lemma=ni
wa
features...upos=PRON
lemma=wa
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Oṣù méjìlá sẹ́yìn , ní oṣù Ọ̀pẹ ọdún 2017 , Ilé-iṣẹ́ Ọkọ̀ òfuurufú Ethiopia fún ìgbà àkókọ́ gbé ikọ̀ òṣìṣẹ́bìrin fò .gbé
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=gbé
ikọ̀
features...upos=NOUN
lemma=ikọ̀
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Bíótilẹ̀jẹ́pé kòì tíì wá sí gbangba kí ó ṣàlàyé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ , àwọn ẹlòmíràn ń sọ pé fúnra rẹ̀ ni ó yọ ọ́ kí ọ̀ràn tó wà nílẹ̀ lè tán bọ̀rọ̀ .ṣàlàyé
features...upos=VERB
deprel=acl
lemma=ṣàlàyé
ohun
features...upos=NOUN
lemma=ohun
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Orùn ìwòjú tí ó wà ní ilé ọnà Metropolitant ( Met ) jọ mọ́ èyí tí wọ́n fi àwọn ọkùnrin Àgùdà ṣẹ̀ṣọ́ rẹ̀ ( ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ti bàjẹ́ díẹ̀ ) , Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé , ọrùn ìwòjú èyí tí ó wà ní ilé ọnà Bìrìtìkó jẹ́ èyí tí wọ́n fi igi tàbí irin gbẹ́ .mọ́
features...upos=VERB
deprel=parataxis
lemma=mọ́
èyí
features...upos=PRON
lemma=èyí
PronType=Dem
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Àwùjọ Wikipédíà ṣe Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà yìí lati ṣe àpèjúwe ọ̀nàn tó dára jùlọ lati ṣàgbékalẹ́ ọ̀rọ̀ , yanjú ìjà àti lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìlépa wa fún ṣiṣẹda ìmọ ọfẹ .ṣe
features...upos=VERB
deprel=advcl
lemma=ṣe
àpèjúwe
features...upos=NOUN
lemma=àpèjúwe
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Wọ́n pè é ní “adarí ayérayé tí ó ga jù" .pè
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=pè
é
features...upos=PRON
lemma=é
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
E : Ẹ̀n… Ẹ ti fìgbà kan ní ọkùnrin tí ó dára ní ipò náà , àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?ní
features...upos=VERB
deprel=compound:svc
lemma=ní
ọkùnrin
features...upos=NOUN
lemma=ọkùnrin
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Bí ó ti lẹ̀ jé pé Ọbásanjọ́ ti Buhari lẹ́yìn láti leè yege ní ọdún 2015 , a kò leè sọ pé àtìlẹyìn rẹ̀ nìkan ni ó gbé e dé ipò Ààrẹ .dé
features...upos=VERB
deprel=compound:svc
lemma=dé
ipò
features...upos=NOUN
lemma=ipò
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Èmi sì ní àwọn àgùntàn mìíràn , tí kìí ṣe agbo yìí : àwọn ni èmi yóò mú wá pẹ̀lú , wọn ó sì gbọ́ ohùn mi ; wọn ó sì jẹ́ agbo kan , olùsọ́ - àgùntàn kan .mú
features...upos=VERB
deprel=parataxis
lemma=mú
àwọn
features...upos=PRON
lemma=àwọn
PronType=Ind
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Àwọn Júù sì dá a lóhùn pé , “ Àwa kò sọ ọ́ ní òkúta nítorí iṣẹ́ rere , ṣùgbọ́n nítorí ọ̀rọ̀ - ọ̀dì : àti nítorí ìwọ tí í ṣe ènìyàn ń fi ara rẹ pe Ọlọ́run . ”ṣe
features...upos=VERB
deprel=xcomp
lemma=ṣe
ènìyàn
features...upos=NOUN
lemma=ènìyàn
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Láti ìparí ọdún 2016 , a ti fi ìtàn àwọn ènìyàn ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àyíká fún àwọn èwe ní ìgbèríko Laos àti Thailand .ṣe
features...upos=VERB
deprel=compound:svc
lemma=ṣe
ìdánilẹ́kọ̀ọ́
features...upos=NOUN
lemma=ìdánilẹ́kọ̀ọ́
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ṣùgbọ́n èmi wí fún un yín pé , ẹnikẹ́ni tí ó bínú sí arákùnrin rẹ̀ yóò wà nínú ewu ìdájọ́ . Ẹnikẹ́ni ti ó ba wí fun arakùnrin rẹ̀ pé , ‘ Ráákà ’ yóò fara hàn níwájú Sahẹ́ńdìrì ; ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá wí pé ‘ Ìwọ wèrè ! ’ yóò wà nínú ewu iná ọ̀run àpáàdì .fun
features...upos=VERB
deprel=compound:svc
lemma=fun
arakùnrin
features...upos=NOUN
lemma=arakùnrin
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Díẹ̀ lára àwọn abódiakọ-akọ́diabo ènìyàn du ipò ìjọba nínú Ìbò ọdún 2018 fún ìgbà àkọ́kọ́ .du
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=du
ipò
features...upos=NOUN
lemma=ipò
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Àwọn olólùfẹ́ẹ Soca kò le è béèrè ju bẹ́ẹ̀ lọ .béèrè
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=béèrè
è
features...upos=PRON
lemma=è
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú , ībòjú kékeré òhún tí kò gígùn rẹ̀ kò ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú , Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn ( tí ó sì maa bá mu ) tàbí bi " ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí " ( èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu ) .ju
features...upos=VERB
deprel=conj
lemma=ju
ìwòn
features...upos=NOUN
lemma=ìwòn
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn àti ẹgbẹ́ ajàfómìnira ti sọ̀rọ̀ síta láti gbèjà Abubacar tí wọ́n sọ pé mímú tí wọ́n mú un àti àtìmọ́lée rẹ̀ ti dẹ́rùba òmìnira ẹni láti sọ̀rọ̀ .gbèjà
features...upos=VERB
deprel=ccomp
lemma=gbèjà
Abubacar
features...upos=PROPN
lemma=Abubacar
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Bíótiwùkíórí , ó ní láti bá agbára ìwàlóríoyè afigagbága rẹ̀ takọ̀ngbọ̀n .bá
features...upos=VERB
deprel=ccomp
lemma=bá
agbára
features...upos=NOUN
lemma=agbára
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Àwọn ọmọ náà tí wọn kò ju ọmọ ọdún 15 sí 17 yóò ṣe ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún bí wọ́n bá jẹ̀bi ẹ̀sùn ìtàbùkù bá Ààrẹ orílẹ̀-èdè .ṣe
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=ṣe
ẹ̀wọ̀n
features...upos=NOUN
lemma=ẹ̀wọ̀n
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Níbẹ̀ , wọ́n fi ẹ̀kọ́ kún ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìtàkùrọ̀sọ àti kọ́ nípa ipa àyípadà ojú-ọjọ́ .kún
features...upos=VERB
deprel=compound:svc
lemma=kún
ẹ̀kọ́
features...upos=NOUN
lemma=ẹ̀kọ́
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Kò sí òótọ́ ní ibẹ̀ , ayédèrú ìròyìn ni , irọ́ funfun báláú nini
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=ni
òótọ́
features...upos=NOUN
lemma=òótọ́
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nítorí wípé kò sí iṣẹ́ fún wọn , àwọn abódiakọ-akọ́diabo ènìyàn kò ní ṣíṣe ju kí wọn ó ṣe òwò nọ̀bì láti rí oúnjẹ òòjọ́ .sí
features...upos=VERB
deprel=advcl
lemma=sí
iṣẹ́
features...upos=NOUN
lemma=iṣẹ́
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Wọ́n tún ṣe bẹ́ẹ̀ , wọ́n mú okùn ìkòkò ìse-ìrẹsì .mú
features...upos=VERB
deprel=aux
lemma=mú
okùn
features...upos=NOUN
lemma=okùn
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ọ̀dọ́ erin mìíràn , Ayeyar Maung náà rí nǹkan .rí
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=rí
nǹkan
features...upos=NOUN
lemma=nǹkan
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Bí olóṣèlú ẹgbẹ́ alátakò , àwọn méjèèjì kò ní ẹ̀rí tí ó dájú tí yóò fi ìdí ẹ̀sùn tí ó fi kan ìjọba àná múlẹ̀ .fi
features...upos=VERB
deprel=advcl
lemma=fi
ìdí
features...upos=NOUN
lemma=ìdí
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Wéré tí ó sọ ọ́ sílẹ̀ , logan ni ó rí ọ̀nà ní iwájúu rẹ̀ .rí
features...upos=VERB
deprel=aux
lemma=rí
ọ̀nà
features...upos=NOUN
lemma=ọ̀nà
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí .tẹ̀lé
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=tẹ̀lé
ìjápọ̀
features...upos=NOUN
lemma=ìjápọ̀
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Bí ojú rẹ ọ̀tún bá mú ọ dẹ́sẹ̀ , yọ ọ́ jáde , kí ó sì sọ ọ́ nù . Ó sàn kí ẹ̀ya ara rẹ kan ṣègbé , ju kí a gbé gbogbo ara rẹ jù sínú iná ọ̀run àpáàdì .gbé
features...upos=VERB
deprel=conj
lemma=gbé
ara
features...upos=NOUN
lemma=ara
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Àwọn òbí wọn kò sì wá bá wa rí pé ohun tí a ń kọ́ ọmọ wọn kò kájú ìwọ̀n , kò ṣẹlẹ̀ ríbá
features...upos=VERB
deprel=aux
lemma=bá
wa
features...upos=PRON
lemma=wa
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ìwé ìròyìn Punch ṣe ìfojúsùn “ìpèsípò" gẹ́gẹ́ bí “àìròtẹ́lẹ̀ " àti pé ó ti pín ìlú yẹ́bẹyẹ̀bẹ .ṣe
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=ṣe
ìfojúsùn
features...upos=NOUN
lemma=ìfojúsùn
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Akọ̀ròyìn Vladimir Villegas sọ wípé kò rí bẹ́ẹ̀ mọ́ wípé ìjọba ni ó fi ọwọ́ agbára mú u :rí
features...upos=VERB
deprel=advcl
lemma=rí
bẹ́ẹ̀
features...upos=NOUN
lemma=bẹ́ẹ̀
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Mo wo ìtàkùrọsọ àkọ́kọ́ tí Ilham Aliyev ṣe pẹ̀lú oníròyìn ilẹ̀ yìí kan .wo
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=wo
ìtàkùrọsọ
features...upos=NOUN
lemma=ìtàkùrọsọ
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ní oṣù Ọ̀wàrà ọdún-un 2018 , Joenia tún gbajúmọ̀ sí i nígbà tí ó di ọmọ ìbílẹ̀ lóbìnrin àkọ́kọ́ tí wọn yóò yàn sípò nínú ìgbìmọ̀ ìjọba .di
features...upos=VERB
deprel=ccomp
lemma=di
ọmọ
features...upos=NOUN
lemma=ọmọ
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ọ̀kan ní ara àwọn àtúntò tí a fẹ́ẹ́ mú bá àjọ LAWMA ni ìyẹnbá
features...upos=VERB
deprel=compound:svc
lemma=bá
àjọ
features...upos=NOUN
lemma=àjọ
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ní iwájú orí ìbòjú méjì yìí , ìlà mẹ́rin wà níbẹ̀ , tí ó sì dúro ṣangílítí sí òkè ojú kànkan , irin méjì sì ṣe àpèjúwe ilà yìí .ṣe
features...upos=VERB
deprel=conj
lemma=ṣe
àpèjúwe
features...upos=NOUN
lemma=àpèjúwe
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn , ó gun orí òkè lọ ó sì jókòó . Àwọn ọmọ - ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ wá .gun
features...upos=VERB
deprel=conj
lemma=gun
orí
features...upos=NOUN
lemma=orí
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Ìwò káàkiri ọdún-un 2010 kan fi hàn wípé ìdá 94 ọmọ bíbí Tanzania ní ìgbàgbọ́ nínú agbára Àjẹ́ .ní
features...upos=VERB
deprel=advcl
lemma=ní
ìgbàgbọ́
features...upos=NOUN
lemma=ìgbàgbọ́
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi , mo sì mú - un dákẹ́jẹ́ẹ́ , bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú : ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú .fi
features...upos=VERB
deprel=acl
lemma=fi
ọwọ
features...upos=NOUN
lemma=ọwọ
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Jésù dá wọn lóhùn pé , “ A kò ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín pé , ‘ Mo ti wí pé , Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́ ’ ?dá
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=dá
wọn
features...upos=PRON
lemma=wọn
Case=Acc
Number=Plur
Person=3
PronType=Prs
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
Nítorí náà ni Baba mi ṣe fẹ́ràn mi , nítorí tí mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀ , kí èmi lè tún gbà á .ṣe
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=ṣe
mi
features...upos=PRON
lemma=mi
Case=Acc
Number=Sing
Person=1
PronType=Prs
deprel=obj
UD_Yoruba-YTB
FLAC ti ń ṣe àtọ́nàa ìṣòfin tí ó tako ìṣọdẹ-àjẹ́ ní Jharkhand .tako
features...upos=VERB
deprel=acl
lemma=tako
ìṣọdẹ-àjẹ́
features...upos=NOUN
lemma=ìṣọdẹ-àjẹ́
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Títì tí àwọn ológun ti Abubacar mọ́lé jẹ́ ìpalára fún ẹ̀tọ́ rẹ pẹ̀lú mímú tí wọ́n mú un láìsí ìdí tí wọ́n fi ìdí ẹ múlẹ̀ .ti
features...upos=VERB
deprel=acl
lemma=ti
Abubacar
features...upos=PROPN
lemma=Abubacar
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Ní orí ìlànà ètò ìpàdé àkọ́kọ́ ìgbìmọ̀ọ Tanzania ọdún-un 2019 ni ìdámọ̀ràn àtúnṣe sí Òfin Ẹgbẹ́ Òṣèlú , tí ó ti ní àríyànjiyàn lemọ́lemọ́ nínúu ìṣèlú tí nǹkan kò ṣe ẹnu re .ṣe
features...upos=VERB
deprel=acl
lemma=ṣe
ẹnu
features...upos=NOUN
lemma=ẹnu
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Òṣìṣẹ́ àgọ̀ kan ń rọ Ayeyar Maung ní oúnjẹ .ní
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=ní
oúnjẹ
features...upos=NOUN
lemma=oúnjẹ
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
A bá a kẹ́dùn ipò tí ó wà .bá
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=bá
a
features...upos=PRON
lemma=a
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD
Níwọ̀n ìgbà tí òde ti já ọgbọ́n àtamátàsè , ẹyẹ Eneke náà ti kọ́ fífò láì bà .kọ́
features...upos=VERB
deprel=root
lemma=kọ́
fífò
features...upos=NOUN
lemma=fífò
deprel=obj
UD_Yoruba-AfriSUD