Example items (sample of 50)
| sen_str | Verb_form | Verb_features | obj_form | obj_features | treebank_link |
|---|---|---|---|---|---|
| Ohun tí ó mú èyí bani nínú jẹ́ jù ni fún ẹni láti rí ikú tí ó pa ẹ̀gbọ́n ẹni . | pa | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=pa | ẹ̀gbọ́n | features...upos=NOUNlemma=ẹ̀gbọ́n deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Nígbà tí Màríà sì dé ibi tí Jésù wà , tí ó sì rí i , ó wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀ , ó wí fún un pé , “ Olúwa , ìbáṣe pé ìwọ ti wà níhín-ín , arákùnrin mi kì bá kú . ” | dé | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=dé | ibi | features...upos=NOUNlemma=ibi deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| inúu wa dùn nítorí wípé a fún àwọn ènìyàn mìíràn ní ìmísí ni ." | ní | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=ní | ìmísí | features...upos=NOUNlemma=ìmísí deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Wọ́n sì fi í rẹ́rín . Ṣùgbọ́n ó sọ fún gbogbo wọn láti bọ́ sí ìta , ó mú baba àti ìyá ọmọ náà , àti àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ mẹ́ta . Ó sì wọ inú yàrá tí ọmọbìnrin náà gbé dùbúlẹ̀ sí . | rẹ́rín | features...upos=VERBdeprel=root lemma=rẹ́rín | í | features...upos=PRONlemma=í Case=Acc Number=Sing Person=3 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Nítorí náà àwọn Júù wá dúró yí i ká , wọ́n sì wí fún un pé , “ Ìwọ ó ti mú wa ṣe iyèméjì pẹ́ tó ? Bí ìwọ bá ni Kírísítì náà , wí fún wa gbangba . ” | mú | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=mú | wa | features...upos=PRONlemma=wa Case=Acc Number=Plur Person=1 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Olórí ni wa , aronújinlẹ̀ ni wa , ọlọ́pọlọ pípé ni wa , onímọ̀ ni wa . | ni | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=ni | wa | features...upos=PRONlemma=wa deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Oṣù méjìlá sẹ́yìn , ní oṣù Ọ̀pẹ ọdún 2017 , Ilé-iṣẹ́ Ọkọ̀ òfuurufú Ethiopia fún ìgbà àkókọ́ gbé ikọ̀ òṣìṣẹ́bìrin fò . | gbé | features...upos=VERBdeprel=root lemma=gbé | ikọ̀ | features...upos=NOUNlemma=ikọ̀ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bíótilẹ̀jẹ́pé kòì tíì wá sí gbangba kí ó ṣàlàyé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ , àwọn ẹlòmíràn ń sọ pé fúnra rẹ̀ ni ó yọ ọ́ kí ọ̀ràn tó wà nílẹ̀ lè tán bọ̀rọ̀ . | ṣàlàyé | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=ṣàlàyé | ohun | features...upos=NOUNlemma=ohun deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Orùn ìwòjú tí ó wà ní ilé ọnà Metropolitant ( Met ) jọ mọ́ èyí tí wọ́n fi àwọn ọkùnrin Àgùdà ṣẹ̀ṣọ́ rẹ̀ ( ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ti bàjẹ́ díẹ̀ ) , Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé , ọrùn ìwòjú èyí tí ó wà ní ilé ọnà Bìrìtìkó jẹ́ èyí tí wọ́n fi igi tàbí irin gbẹ́ . | mọ́ | features...upos=VERBdeprel=parataxis lemma=mọ́ | èyí | features...upos=PRONlemma=èyí PronType=Dem deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Àwùjọ Wikipédíà ṣe Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà yìí lati ṣe àpèjúwe ọ̀nàn tó dára jùlọ lati ṣàgbékalẹ́ ọ̀rọ̀ , yanjú ìjà àti lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìlépa wa fún ṣiṣẹda ìmọ ọfẹ . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=ṣe | àpèjúwe | features...upos=NOUNlemma=àpèjúwe deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Wọ́n pè é ní “adarí ayérayé tí ó ga jù" . | pè | features...upos=VERBdeprel=root lemma=pè | é | features...upos=PRONlemma=é deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| E : Ẹ̀n… Ẹ ti fìgbà kan ní ọkùnrin tí ó dára ní ipò náà , àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? | ní | features...upos=VERBdeprel=compound:svc lemma=ní | ọkùnrin | features...upos=NOUNlemma=ọkùnrin deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bí ó ti lẹ̀ jé pé Ọbásanjọ́ ti Buhari lẹ́yìn láti leè yege ní ọdún 2015 , a kò leè sọ pé àtìlẹyìn rẹ̀ nìkan ni ó gbé e dé ipò Ààrẹ . | dé | features...upos=VERBdeprel=compound:svc lemma=dé | ipò | features...upos=NOUNlemma=ipò deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Èmi sì ní àwọn àgùntàn mìíràn , tí kìí ṣe agbo yìí : àwọn ni èmi yóò mú wá pẹ̀lú , wọn ó sì gbọ́ ohùn mi ; wọn ó sì jẹ́ agbo kan , olùsọ́ - àgùntàn kan . | mú | features...upos=VERBdeprel=parataxis lemma=mú | àwọn | features...upos=PRONlemma=àwọn PronType=Ind deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Àwọn Júù sì dá a lóhùn pé , “ Àwa kò sọ ọ́ ní òkúta nítorí iṣẹ́ rere , ṣùgbọ́n nítorí ọ̀rọ̀ - ọ̀dì : àti nítorí ìwọ tí í ṣe ènìyàn ń fi ara rẹ pe Ọlọ́run . ” | ṣe | features...upos=VERBdeprel=xcomp lemma=ṣe | ènìyàn | features...upos=NOUNlemma=ènìyàn deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Láti ìparí ọdún 2016 , a ti fi ìtàn àwọn ènìyàn ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àyíká fún àwọn èwe ní ìgbèríko Laos àti Thailand . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=compound:svc lemma=ṣe | ìdánilẹ́kọ̀ọ́ | features...upos=NOUNlemma=ìdánilẹ́kọ̀ọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ṣùgbọ́n èmi wí fún un yín pé , ẹnikẹ́ni tí ó bínú sí arákùnrin rẹ̀ yóò wà nínú ewu ìdájọ́ . Ẹnikẹ́ni ti ó ba wí fun arakùnrin rẹ̀ pé , ‘ Ráákà ’ yóò fara hàn níwájú Sahẹ́ńdìrì ; ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá wí pé ‘ Ìwọ wèrè ! ’ yóò wà nínú ewu iná ọ̀run àpáàdì . | fun | features...upos=VERBdeprel=compound:svc lemma=fun | arakùnrin | features...upos=NOUNlemma=arakùnrin deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Díẹ̀ lára àwọn abódiakọ-akọ́diabo ènìyàn du ipò ìjọba nínú Ìbò ọdún 2018 fún ìgbà àkọ́kọ́ . | du | features...upos=VERBdeprel=root lemma=du | ipò | features...upos=NOUNlemma=ipò deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn olólùfẹ́ẹ Soca kò le è béèrè ju bẹ́ẹ̀ lọ . | béèrè | features...upos=VERBdeprel=root lemma=béèrè | è | features...upos=PRONlemma=è deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú , ībòjú kékeré òhún tí kò gígùn rẹ̀ kò ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú , Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn ( tí ó sì maa bá mu ) tàbí bi " ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí " ( èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu ) . | ju | features...upos=VERBdeprel=conj lemma=ju | ìwòn | features...upos=NOUNlemma=ìwòn deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn àti ẹgbẹ́ ajàfómìnira ti sọ̀rọ̀ síta láti gbèjà Abubacar tí wọ́n sọ pé mímú tí wọ́n mú un àti àtìmọ́lée rẹ̀ ti dẹ́rùba òmìnira ẹni láti sọ̀rọ̀ . | gbèjà | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=gbèjà | Abubacar | features...upos=PROPNlemma=Abubacar deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bíótiwùkíórí , ó ní láti bá agbára ìwàlóríoyè afigagbága rẹ̀ takọ̀ngbọ̀n . | bá | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=bá | agbára | features...upos=NOUNlemma=agbára deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn ọmọ náà tí wọn kò ju ọmọ ọdún 15 sí 17 yóò ṣe ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún bí wọ́n bá jẹ̀bi ẹ̀sùn ìtàbùkù bá Ààrẹ orílẹ̀-èdè . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ṣe | ẹ̀wọ̀n | features...upos=NOUNlemma=ẹ̀wọ̀n deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Níbẹ̀ , wọ́n fi ẹ̀kọ́ kún ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìtàkùrọ̀sọ àti kọ́ nípa ipa àyípadà ojú-ọjọ́ . | kún | features...upos=VERBdeprel=compound:svc lemma=kún | ẹ̀kọ́ | features...upos=NOUNlemma=ẹ̀kọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Kò sí òótọ́ ní ibẹ̀ , ayédèrú ìròyìn ni , irọ́ funfun báláú ni | ni | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ni | òótọ́ | features...upos=NOUNlemma=òótọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Nítorí wípé kò sí iṣẹ́ fún wọn , àwọn abódiakọ-akọ́diabo ènìyàn kò ní ṣíṣe ju kí wọn ó ṣe òwò nọ̀bì láti rí oúnjẹ òòjọ́ . | sí | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=sí | iṣẹ́ | features...upos=NOUNlemma=iṣẹ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Wọ́n tún ṣe bẹ́ẹ̀ , wọ́n mú okùn ìkòkò ìse-ìrẹsì . | mú | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=mú | okùn | features...upos=NOUNlemma=okùn deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ọ̀dọ́ erin mìíràn , Ayeyar Maung náà rí nǹkan . | rí | features...upos=VERBdeprel=root lemma=rí | nǹkan | features...upos=NOUNlemma=nǹkan deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bí olóṣèlú ẹgbẹ́ alátakò , àwọn méjèèjì kò ní ẹ̀rí tí ó dájú tí yóò fi ìdí ẹ̀sùn tí ó fi kan ìjọba àná múlẹ̀ . | fi | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=fi | ìdí | features...upos=NOUNlemma=ìdí deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Wéré tí ó sọ ọ́ sílẹ̀ , logan ni ó rí ọ̀nà ní iwájúu rẹ̀ . | rí | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=rí | ọ̀nà | features...upos=NOUNlemma=ọ̀nà deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí . | tẹ̀lé | features...upos=VERBdeprel=root lemma=tẹ̀lé | ìjápọ̀ | features...upos=NOUNlemma=ìjápọ̀ deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Bí ojú rẹ ọ̀tún bá mú ọ dẹ́sẹ̀ , yọ ọ́ jáde , kí ó sì sọ ọ́ nù . Ó sàn kí ẹ̀ya ara rẹ kan ṣègbé , ju kí a gbé gbogbo ara rẹ jù sínú iná ọ̀run àpáàdì . | gbé | features...upos=VERBdeprel=conj lemma=gbé | ara | features...upos=NOUNlemma=ara deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Àwọn òbí wọn kò sì wá bá wa rí pé ohun tí a ń kọ́ ọmọ wọn kò kájú ìwọ̀n , kò ṣẹlẹ̀ rí | bá | features...upos=VERBdeprel=aux lemma=bá | wa | features...upos=PRONlemma=wa deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìwé ìròyìn Punch ṣe ìfojúsùn “ìpèsípò" gẹ́gẹ́ bí “àìròtẹ́lẹ̀ " àti pé ó ti pín ìlú yẹ́bẹyẹ̀bẹ . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ṣe | ìfojúsùn | features...upos=NOUNlemma=ìfojúsùn deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Akọ̀ròyìn Vladimir Villegas sọ wípé kò rí bẹ́ẹ̀ mọ́ wípé ìjọba ni ó fi ọwọ́ agbára mú u : | rí | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=rí | bẹ́ẹ̀ | features...upos=NOUNlemma=bẹ́ẹ̀ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Mo wo ìtàkùrọsọ àkọ́kọ́ tí Ilham Aliyev ṣe pẹ̀lú oníròyìn ilẹ̀ yìí kan . | wo | features...upos=VERBdeprel=root lemma=wo | ìtàkùrọsọ | features...upos=NOUNlemma=ìtàkùrọsọ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ní oṣù Ọ̀wàrà ọdún-un 2018 , Joenia tún gbajúmọ̀ sí i nígbà tí ó di ọmọ ìbílẹ̀ lóbìnrin àkọ́kọ́ tí wọn yóò yàn sípò nínú ìgbìmọ̀ ìjọba . | di | features...upos=VERBdeprel=ccomp lemma=di | ọmọ | features...upos=NOUNlemma=ọmọ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ọ̀kan ní ara àwọn àtúntò tí a fẹ́ẹ́ mú bá àjọ LAWMA ni ìyẹn | bá | features...upos=VERBdeprel=compound:svc lemma=bá | àjọ | features...upos=NOUNlemma=àjọ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ní iwájú orí ìbòjú méjì yìí , ìlà mẹ́rin wà níbẹ̀ , tí ó sì dúro ṣangílítí sí òkè ojú kànkan , irin méjì sì ṣe àpèjúwe ilà yìí . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=conj lemma=ṣe | àpèjúwe | features...upos=NOUNlemma=àpèjúwe deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn , ó gun orí òkè lọ ó sì jókòó . Àwọn ọmọ - ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ wá . | gun | features...upos=VERBdeprel=conj lemma=gun | orí | features...upos=NOUNlemma=orí deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ìwò káàkiri ọdún-un 2010 kan fi hàn wípé ìdá 94 ọmọ bíbí Tanzania ní ìgbàgbọ́ nínú agbára Àjẹ́ . | ní | features...upos=VERBdeprel=advcl lemma=ní | ìgbàgbọ́ | features...upos=NOUNlemma=ìgbàgbọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi , mo sì mú - un dákẹ́jẹ́ẹ́ , bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú : ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú . | fi | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=fi | ọwọ | features...upos=NOUNlemma=ọwọ deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Jésù dá wọn lóhùn pé , “ A kò ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín pé , ‘ Mo ti wí pé , Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́ ’ ? | dá | features...upos=VERBdeprel=root lemma=dá | wọn | features...upos=PRONlemma=wọn Case=Acc Number=Plur Person=3 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Nítorí náà ni Baba mi ṣe fẹ́ràn mi , nítorí tí mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀ , kí èmi lè tún gbà á . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ṣe | mi | features...upos=PRONlemma=mi Case=Acc Number=Sing Person=1 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| FLAC ti ń ṣe àtọ́nàa ìṣòfin tí ó tako ìṣọdẹ-àjẹ́ ní Jharkhand . | tako | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=tako | ìṣọdẹ-àjẹ́ | features...upos=NOUNlemma=ìṣọdẹ-àjẹ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Títì tí àwọn ológun ti Abubacar mọ́lé jẹ́ ìpalára fún ẹ̀tọ́ rẹ pẹ̀lú mímú tí wọ́n mú un láìsí ìdí tí wọ́n fi ìdí ẹ múlẹ̀ . | ti | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=ti | Abubacar | features...upos=PROPNlemma=Abubacar deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ní orí ìlànà ètò ìpàdé àkọ́kọ́ ìgbìmọ̀ọ Tanzania ọdún-un 2019 ni ìdámọ̀ràn àtúnṣe sí Òfin Ẹgbẹ́ Òṣèlú , tí ó ti ní àríyànjiyàn lemọ́lemọ́ nínúu ìṣèlú tí nǹkan kò ṣe ẹnu re . | ṣe | features...upos=VERBdeprel=acl lemma=ṣe | ẹnu | features...upos=NOUNlemma=ẹnu deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Òṣìṣẹ́ àgọ̀ kan ń rọ Ayeyar Maung ní oúnjẹ . | ní | features...upos=VERBdeprel=root lemma=ní | oúnjẹ | features...upos=NOUNlemma=oúnjẹ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| A bá a kẹ́dùn ipò tí ó wà . | bá | features...upos=VERBdeprel=root lemma=bá | a | features...upos=PRONlemma=a deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Níwọ̀n ìgbà tí òde ti já ọgbọ́n àtamátàsè , ẹyẹ Eneke náà ti kọ́ fífò láì bà . | kọ́ | features...upos=VERBdeprel=root lemma=kọ́ | fífò | features...upos=NOUNlemma=fífò deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |