Example items (sample of 50)
| sen_str | Aux_form | Aux_features | obj_form | obj_features | treebank_link |
|---|---|---|---|---|---|
| Nítorí wípé kò sí iṣẹ́ fún wọn , àwọn abódiakọ-akọ́diabo ènìyàn kò ní ṣíṣe ju kí wọn ó ṣe òwò nọ̀bì láti rí oúnjẹ òòjọ́ . | ó | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ó Case=Nom SubjAuxCount=1 | òwò | features...upos=NOUNlemma=òwò deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹsẹ̀ẹ rẹ̀ kan ti lu páḿpẹ́ àwọn ajérangbépa . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | páḿpẹ́ | features...upos=NOUNlemma=páḿpẹ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Bákan náà , ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín kí ó mọ́lẹ níwájú ènìyàn , kí wọ́n lè máa rí iṣẹ́ rere yín , kí wọn lè máa yin baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ní ògo . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ògo | features...upos=NOUNlemma=ògo deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Nítorí pé a ti ń fún un ní èsì fún ọdún pípẹ́ . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=2+ | un | features...upos=PRONlemma=un deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ilé-ìwé ti gbé ẹsẹ̀ lé ìṣẹ̀ṣọ́ọ Kérésìmesì nínú ọgbà ó sì ti sọ pàṣìpàrọ̀ ẹ̀bùn di èèwọ̀ ní ìpolongo ìtako àjọ̀dún Òyìnbó . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=2+ | pàṣìpàrọ̀ | features...upos=NOUNlemma=pàṣìpàrọ̀ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ó tún mú ẹnu bà á pé àwọn máa parí ọjà náà ní àìpẹ́ , àwọn kò ní fi fa ilẹ̀ rárá | máa | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=máa SubjAuxCount=1 | ọjà | features...upos=NOUNlemma=ọjà deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jésù kò gbà fún un , ṣùgbọ́n ó wí fún un pé , “ Lọ sí ilé sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí rẹ , kí o sì sọ fún wọn bí Ọlọ́run ti ṣe ohun ńlá fún ọ , àti bí ó sì ti ṣàánú fún ọ . ” | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ohun | features...upos=NOUNlemma=ohun deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| “ Bá ọ̀tá rẹ làjà kánkán , ẹni tí ó ń gbé ọ lọ sí ilé ẹjọ́ . Ṣe é nígbà ti ó wà ní ọ̀nà pẹ̀lú rẹ , bí bẹ́ẹ̀ kọ́ yóò fà ọ́ lé onídajọ ní ọwọ́ , onídájọ́ yóò sí fá ọ lé àwọn ẹ̀sọ́ ní ọwọ́ , wọ́n a sì sọ ọ́ sínú túbú . | a | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=a SubjAuxCount=1 | ọ́ | features...upos=PRONlemma=ọ́ Case=Acc Number=Sing Person=2 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Torí ìdí èyí máa bá wa ronú ! | máa | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=máa SubjAuxCount=2+ | wa | features...upos=PRONlemma=wa deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Irú àwòrán yìí kò wọ́pọ̀ ní iṣẹ́ ọnà ilẹ̀ Benin , àti pé ipò Idia , tí iṣẹ̀ṣe àwọn Edo mọ̀ sí " obìnrin kan ṣoṣo tó lọ sógun " , tí ó da yàtọ̀ , tí wọ́n sí dá oyèIyoba tàbí Ìyá Olori ̀́n sílẹ̀ fun Ìwérí rẹ̀ jẹ́ ara irú irun tí wọ́n ń pè ní ẹnu àparò , tí a lè rí dáadára ní àfihàn orí edẹ Olorì Idia . | lè | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=lè SubjAuxCount=1 | edẹ | features...upos=NOUNlemma=edẹ deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ihò tí ó wà ní ibi oun ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ àti ibi ọrùn rẹ̀ jẹ́ àpẹẹrẹ ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn tí àwọn ọkùnrin Àgùdà maa ń fi ṣẹ̀ṣọ́ , tí ó sì jẹ́ wípé àwòrán mọ́kànlá bẹ́ẹ̀ wà ní ilé ọnà ìbòjú tí Bìrìtìkó àti pé mẹ́tàlá wà ní ilé ọnà Met tí ó ṣe àfihàn àwọn ọkùnrin Àgùdá tí wọ́n múra bí àwọn ènìyàn dúdú . | jẹ́ | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=jẹ́ SubjAuxCount=1 | ìlẹ̀kẹ̀ | features...upos=NOUNlemma=ìlẹ̀kẹ̀ deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| A lò ó pẹ̀lú àṣẹ . | lò | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=lò SubjAuxCount=1 | ó | features...upos=PRONlemma=ó deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ìwà tí ó jẹ́ gbòògì àwọn ìpèníjà wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bíi ti òfin ń sọ fún ọmọ-ìlú pé ohùn-un wọn ṣe kókó . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ọmọ-ìlú | features...upos=NOUNlemma=ọmọ-ìlú deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹgbẹ́ òṣèlú-ìpínlẹ̀ ti kọ ẹ̀yìn sí àjọ̀dún Òyìnbó . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ẹ̀yìn | features...upos=NOUNlemma=ẹ̀yìn deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn ajìjàngbara sọ wípé ìgbàgbọ́-asán tí ó rinlẹ̀ ní ìgbèríko ni ó ń fa ìwà pálapalà náà . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ìwà | features...upos=NOUNlemma=ìwà deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jésù sì ń bá a lọ . Ọ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn sì ń tọ̀ Ọ́ lẹ́yìn . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ọ́ | features...upos=NOUNlemma=ọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Àwọn orin wọ̀nyìí kò yé Lhamo , bó ṣe jẹ́ pé kò mọ èdèe Mandarin Ilẹ̀ China sọ . | kò | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=kò SubjAuxCount=1 | Lhamo | features...upos=PROPNlemma=Lhamo deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn Àgùdà jẹ́ oníṣòwò pẹ̀lú àwọn Benin nígbàyẹn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ , ó jẹ́ àpẹrẹ́ àjọṣepọ̀ láàrin omi àti ilẹ̀ . | jẹ́ | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=jẹ́ SubjAuxCount=1 | benin | features...upos=NOUNlemma=Benin deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Wọ́n ti fi àmì-ẹ̀yẹ ìdánimọ̀ yìí kan náà fún Nelson Mandela àti Malala rí . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | àmì-ẹ̀yẹ | features...upos=NOUNlemma=àmì-ẹ̀yẹ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Nígbà ìkọ́ṣẹ́ , bí ọmọ Mauritania aláwọ̀ funfun kan kò bá ṣe dáadáa , wọn á ṣì borí aláwọ̀ dúdú mìíràn . | kò | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=kò SubjAuxCount=2+ | dáadáa | features...upos=NOUNlemma=dáadáa deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwa náà ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ , pàápàá ní ti ọ̀rọ̀ ìfọwọ́ pẹ̀lú omi àti ọṣẹ | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | iṣẹ́ | features...upos=NOUNlemma=iṣẹ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹnikẹ́ni ti ó bá rú òfin tí ó tilẹ̀ kéré jù lọ , tí ó sì kọ́ ẹlòmíràn láti ṣe bẹ́ẹ̀ , òun ni yóò kéré jù lọ ní ìjọba ọ̀run , ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ń ṣe wọ́n , tí ó sì ń kọ́ wọn , ni yóò jẹ́ ẹni ńlá ní ìjọba ọ̀run . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | wọn | features...upos=PRONlemma=wọn Case=Acc Number=Plur Person=3 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Aṣọ inujú yìí ni wọ́n máa ń pè ní “àkísà" , èyí tí wọn máa fi ń nu àágùn bí wọ́n bá ń “fò sókè" . | máa | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=máa SubjAuxCount=2+ | àágùn | features...upos=NOUNlemma=àágùn deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè , àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | Yorùbá | features...upos=PROPNlemma=Yorùbá deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ọbásanjọ́ nìkan sì kọ́ ni ọ̀gágun tí ó ti jagun fẹ̀yìntì tí ó ń tàbùkù Buhari . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | Buhari | features...upos=PROPNlemma=Buhari deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Wọ́n sì tún ń wá ọ̀nà láti mú un : ó sì bọ́ lọ́wọ́ wọn . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ọ̀nà | features...upos=NOUNlemma=ọ̀nà deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ìjọba àti àwọn àjọ rẹ̀ máa ń sábà fi èyí ṣe bójúbójú fún ìtẹríbọlẹ̀ òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ . | máa | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=máa SubjAuxCount=1 | èyí | features...upos=NOUNlemma=èyí deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ti ẹnu - ọ̀nà wọlé , Òun ni olùṣọ́ àwọn àgùntàn . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ẹnu | features...upos=NOUNlemma=ẹnu deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Tí ẹ bá ṣàkíyèsí àsìṣe tàbí ẹ ní àbá fún àtúnṣe , ẹ le tọrọ àtúnṣe , nípa títẹ klik sí àjápọ̀ ìsàlẹ̀ , kí ẹ sì tẹ̀lẹ́ àwọn ìlànà ibẹ̀ . | le | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=lè SubjAuxCount=1 | àtúnṣe | features...upos=NOUNlemma=àtúnṣe deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Tí ẹ kò bá ní àkópamọ́ , ẹ le dá ìkan ; lẹ́yìn ọjọ́ 4 àti àtúnṣe 10 , ẹ ó le ṣàtúnṣe àwọn ojúewé àbò díẹ̀ . | le | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=lè SubjAuxCount=1 | ìkan | features...upos=NOUNlemma=ìkan deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Kò kan ẹnikéni bóyá èèyàn féràn àjọyọ̀ tàbí kò fẹ́ , kí ni ó dé tí àwọn ènìyàn ṣe fẹ́ràn láti máa fi túláàsì mú ẹlòmíràn gba èròńgbà ti wọn? | kò | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=Kò SubjAuxCount=2+ | ẹnikéni | features...upos=NOUNlemma=ẹnikéni deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àfilé iye owó náà ti dá awuyewuye sílẹ̀ . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | awuyewuye | features...upos=NOUNlemma=awuyewuye deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn kan ti yan ìṣàjọyọ̀ àjọ̀dún náà ní ìkọ̀kọ̀ . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ìṣàjọyọ̀ | features...upos=NOUNlemma=ìṣàjọyọ̀ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jésù dá wọn lóhùn pé , “ A kò ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín pé , ‘ Mo ti wí pé , Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́ ’ ? | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ọ́ | features...upos=PRONlemma=ọ́ Case=Acc Number=Sing Person=2 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Pierre Nkurunziza ti jẹ ààrẹ ilẹ̀ Burundi láti ọdún 2005 . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ààrẹ | features...upos=NOUNlemma=ààrẹ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ohùn Àgbáyé ti ń jábọ̀ ìròyìn lórí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí fún ọdún mẹ́wàá . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=2+ | ìròyìn | features...upos=NOUNlemma=ìròyìn deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ẹnikẹ́ni ti ó bá rú òfin tí ó tilẹ̀ kéré jù lọ , tí ó sì kọ́ ẹlòmíràn láti ṣe bẹ́ẹ̀ , òun ni yóò kéré jù lọ ní ìjọba ọ̀run , ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ń ṣe wọ́n , tí ó sì ń kọ́ wọn , ni yóò jẹ́ ẹni ńlá ní ìjọba ọ̀run . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | wọ́n | features...upos=PRONlemma=wọ́n Case=Acc Number=Plur Person=3 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Bí a bá kà á ní ẹníméjì , ó ti tó ènìyàn 500 tí ó ti ṣe ìrìnàjò náà . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | ìrìnàjò | features...upos=NOUNlemma=ìrìnàjò deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Jésù kò tíì wọ ìlú , ṣùgbọ́n ó wà ní ibi kan náà tí Mátà ti pàdé rẹ̀ . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | rẹ̀ | features...upos=PRONlemma=rẹ̀ Case=Gen Number=Sing Person=3 PronType=Prs deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀ , Jésù rí i pé gbogbo nǹkan ti dàrú . Ilé kún fún àwọn tí ń sọkún , àti àwọn tí ń pohùnréré ẹkún . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ẹkún | features...upos=NOUNlemma=ẹkún deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ní ọ̀nà kejì , Ezekwesili , Moghalu , Sowore , àwọn “agbára ìkẹ́ta" , jẹ́ ẹgbẹ́ tí ó ń wọ inú ètò ìṣèlú fún ìgbà àkọ́kọ́ . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | inú | features...upos=NOUNlemma=inú deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Mo lè sọ Gẹ̀ẹ́sì ." | lè | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=lè SubjAuxCount=1 | gẹ̀ẹ́sì | features...upos=NOUNlemma=Gẹ̀ẹ́sì deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ó lè rí ìrànwọ́ fún àwọn tí ó ń bá ìparaẹni fà á àti àwọn tí ó wà nínú ìbàjẹ́ ọkàn . | lè | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=lè SubjAuxCount=1 | ìrànwọ́ | features...upos=NOUNlemma=ìrànwọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| kí ó tóó di àsìkò Kòrónà , kì í ṣe ohun kékeré láti ṣiṣẹ́ ọrọ̀-ajé ní ìlú wa yìí | kì | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=kì SubjAuxCount=1 | ohun | features...upos=NOUNlemma=ohun deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Ọlọ́run sì wí pé “ Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà ní ojú ọ̀run , làti pààlà sí àárin ọ̀sán àti òru , kí wọn ó sì máa wà fún àmì láti mọ àwọn àsìkò , àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún , | kí | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=kí SubjAuxCount=2+ | àmì | features...upos=NOUNlemma=àmì deprel=obj | UD_Yoruba-YTB |
| Ìjọ Ajíhìnrere Foursquare ti dá Igbeneghu dúró “lẹ́nu iṣẹ́ ìhìn rere" . | ti | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ti Case=Nom SubjAuxCount=1 | Igbeneghu | features...upos=PROPNlemma=Igbeneghu deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| “Ẹ yé é da ẹlòmíràn , ẹ jọ̀wọ́ a ò fẹ́ aláìṣòdodo aya mọ́ . | yé | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=yé SubjAuxCount=2+ | aláìṣòdodo | features...upos=NOUNlemma=aláìṣòdodo deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| A nílò láti ṣe àyípadà ìgbàgbọ́ pé à ń ṣe ìdíwọ́ fún ìdàgbàsókè tàbí pé à ń ṣe ìpalára fún ẹnikẹ́ni . | ń | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=ń SubjAuxCount=1 | ìdíwọ́ | features...upos=NOUNlemma=ìdíwọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Kò sí òótọ́ ní ibẹ̀ , ayédèrú ìròyìn ni , irọ́ funfun báláú ni | kò | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=Kò SubjAuxCount=2+ | òótọ́ | features...upos=NOUNlemma=òótọ́ deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |
| Àwọn tí wọ́n wò ó sọ àwọn nǹkan tí kò tẹ́ wọn lọ́run , wón sì tún pè fún àyípadà . | kò | features...upos=AUXdeprel=aux lemma=kò SubjAuxCount=1 | wọn | features...upos=PRONlemma=wọn deprel=obj | UD_Yoruba-AfriSUD |